Omo Ologo

Oga Ńlá ní, kò ṣe farawé (ọmọ-ọmọ Moriamo)

Qdot lórúkọ mí (2t upon the beat)

Dem try make dem block my way
God pass dem, I don go Far away
Na God dey run am, kò kán ayé oo (kò kán ayé o)
Oga Ńlá ní, kò ṣe farawé

(Wọn bínú ọmọ ológo)
Àwọn olofo (wọn bínú ọmọ ológo)
They be bad belle people (wọn bínú ọmọ ológo)
They wan' make your world dey o-
(Wọn bínú ọmọ ológo, wọn bínú ọmọ ológo)

Ko m'ológo, kólé lógo oo
Mà báwọn bínú ológo
Olúwa ló mọ ológo

Olofo lòun bínú ológo
T'ówó bádé, t'ọlá bádé, ọ'rẹ' lé dì ọ'tá ẹní
Tóbá dì p'odán tàn, ẹbí lè fẹ pá 'ní
Bà ṣe ń jẹlọ, ahm (wọn bínú)
Bó'wó ṣé ń wọlé (wọn bínú)
Bà ṣe ń gbérà (wọn bínú)
Bà ṣe ń gbé'rí (wọn bínú)
Okíkí ṣé pọ

(Wọn bínú ọmọ ológo)
Àwọn olofo (wọn bínú ọmọ ológo)
They be bad belle people (wọn bínú ọmọ ológo)
They wan' make your world dey o-
Wọn bínú ọmọ ológo (ọmọ-ọmọ Moriamo)
Wọn bínú ọmọ ológo

Tẹ bá l'ajẹ ní ìyá yìn, ajẹ níyá tèmi náà
Tẹ bá n'oṣo ní bàbá yìn, oṣo ní bàbá tèmi náà
B'ẹni Bíbélì, mo ní Quran, b'ẹni Quran, mo ní Bíbélì
Tẹ bá ní Kínní bàbá yìn, ẹ'mí nà ní Kínní bàbá mí (kúrò bẹ yẹn na)
Ẹwà wó àwọn òní ìṣólẹ'nu, wọn sọrọ bí Ọlọ'run
Wọn fẹ mọ ìdì abájọ mí, wọn fẹ mọ́lé Bàbá Alájọ mí
Ìyá wọn bínú, óní, ó má ṣé pé òun ó biruwa
Latayé ligaligali tó fí dì ìgbàyí ooo

(Wọn bínú ọmọ ológo)
Àwọn olofo (wọn bínú ọmọ ológo)
They be bad belle people (wọn bínú ọmọ ológo)
They wan' make your world dey o
(Wọn bínú ọmọ ológo, wọn bínú ọmọ ológo)

Dem try make dem block my way
God pass dem, I don go Far away
Na God dey run am, kò kán ayé oo (kò kán ayé o)
Oga Ńlá ní, kò ṣe farawé

(Wọn bínú ọmọ ológo)
Àwọn olofo (wọn bínú ọmọ ológo)
They be bad belle people (wọn bínú ọmọ ológo)
They wan' make your world dey o
(Wọn bínú ọmọ ológo, wọn bínú ọmọ ológo)

Àjo ń ronú, àjo ń dùnún, lójijì lòdì p'obínú
Ará ń táwọn bà ṣé ń gbé rí (gbé rí o)
Lójijì lòdì pọn ń lérí, lérí, lekà àbòsí oo (àbòsí)
A fọ lọwọ mu Hennessey (Hennessey o)
Kò sí àyè fún alàbòsia (àbòsia)
Olọtẹ ló mà ṣẹ sìn ahn

Ọga wá, Anọbi Omole, ọmọ ìyàwó Anọbi
A fúnni l'oúnjẹ, má wo bẹ, Alagbe tó ń fún Alagbe lówó
Eyan I.B.D Dende
(2T upon the mix)



Credits
Writer(s): Pasuma, Qdot
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link