Akikitan

Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare

Igba ti mo ki o o ofi mi lokan bale
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o otun aye mi se o
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o ofi mi lokan bale
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o otun aye mi se o
Akiikitan o oba eledumare

Baba ti fi mi lokan bale wonder wonder
Baba ti fi mi lokan bale wonder wonder
Baba ti tun aye mi se o wonder wonder
Baba ti tun aye mi se o wonder wonder
Baba ti fi mi lokan bale wonder wonder
Baba ti fi mi lokan bale wonder wonder
Baba ti tun aye mi se o wonder wonder
Baba ti tun aye mi se o wonder wonder

Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare

E kii baba o
E kii baba o
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu
E kii baba o
Arugbo ojo
E kii baba oo
A da gba ma pa ro oye
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu

E kii baba o o
E kii baba o o
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu
E kii baba o
Arugbo ojo
E kii baba oo
A da gba ma pa ro oye
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu

Gbogbo aye te ri yen
Apoti itise lo je o folorun oba
E kii baba o
Oni le ola
E kii baba o
Alagbala,, iyanu
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu

Olori aye
Olori aye
Olori aye
Olori aye
Olori aye soro lorun
Ara san laye
E kii baba o
Alade ogo
E kii baba o
Alade wura
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu
O lori aye
O lori aye
O lori aye
O lori aye
Olori aye soro lorun
Ara san laye
E kii baba o
Alade ola
E kii baba o
Alade wura
Apa nla to so aye ro
Onise iyanu
Eru jeje ninu orun o
O nse gudu gudu

Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o ofi mi lokan bale
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o otun aye mi se o
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o ofi mi lokan bale
Akiikitan o oba eledumare
Igba ti mo ki o o otun aye mi se o
Akiikitan o oba eledumare

Oba to se
To se ike mi o
Oba to se
To se ike mi o
Ti koba se pe
E se ati leyin mi o
Ti ko ba se pe
E se ati leyin mi o
N ko ba si laye
Oba to se
To se ike mi o
Oba to se
To se ike mi o
Ti koba se pe
E se ati leyin mi o
Ti ko ba se pe
E se ati leyin mi o
Nko ba ti si laye

Ato fa ra ti bi oke e se o
Ato fa ra ti bi oke e se o
E yin lo so pe
Kemi wonu isinmi o
E yin lo so pe
Kemi wonu isinmi o
E seun baba
Oba to se
To se ike mi o
Oba to se
To se ike mi o
Ti koba se pe
E se ati leyin mi o
Ti ko ba se pe
E se ati leyin mi o
Nko ba ti si laye

Mo ti sa ko lo
Bi aguntan to so nu
Mo ti sa ko lo
Bi aguntan to so nu
Baba wa mi ri
O gbe mi sejika re
Baba wa mi ri
O gbe mi sejika re
Ayo nla kun okan baba
Oba to se
To se ike mi o
Oba to se
To se ike mi o
Ti koba se pe
E se ati leyin mi o
Ti ko ba se pe
E se ati leyin mi o
Nko ba ti si laye

Aye le pa mi titi
Won ko ma ri mi pa
Ota le pa mi titi
Won ko ma ri mi pa
Won di egbinrin ote
Won ko ma ri mi pa
Oba to se
To se ike mi o
Oba to se
To se ike mi o
Ti koba se pe
E se ati leyin mi o
Ti ko ba se pe
E se ati leyin mi o
Nko ba ti si laye

Jesu mi lo ba mi se o
Jesu mi lo ba mi se o
O hun ta aye so wi pe
Ko se e se
O ti se
Jesu mi lo ba mi se o
O ti ba mi se
Jesu mi lo ba mi se o
O ti se yo ri
O hun ta aye so wi pe
Ko se e se
O ti se
Oba to se
To se ike mi o
Oba to se
To se ike mi o
Ti koba se pe
E se ati leyin mi o
Ti ko ba se pe
E se ati leyin mi o
Nko ba ti si laye



Credits
Writer(s): Ogunlade Peter
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link