Ife Owo
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Olohun lomo inu oyun iya ko towa aye
Olohun lomo inu oyun iya koto bi
B'omo waye b'omo naa ba tin gbon
Obi to bimo naa gbodo ma sho ni
Iya jade lo koto pada wa sile
Gbogbo oun to sele ki iya e o tode
Igba tode lomo nkà bi éyé fun
Toye koni komo naa o dake
Toba dagba koma pada wa túlé
Omo to njiwe ji biro egbe wale
T'obi omo o beere bose ri
Bon o tete mojuto ton kaju
Toba dagba to nféwó ebi won ni
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Otito lere bosewu ko peto
Tori pon leyin todun j'oyin lo
Se reni ti ab banse otito fun
Tonlo inu meji sini egun loje
Kanifura kama gbagbe ara wa
Tori alasiri ore kan o si rara, ifinu we'nu ma npada di íwó ni
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Mowa tewo s'olohun okansoso
Mo tewo s'olohun okansoso
Ma gba iwa mi tori ola aye lasan, òjò kù eda yi omi ágbádá nu
O gbagbe pe ojo leshu koma ro
Kinma fowomi serami laye
Kinma mu ika abami fi bo'nu
Gbami lagbatan allah maje nse
Asise tole mu alanu sa tan
F'ayo sinu aye mio kola o de
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Iwa ti towa leru ka di
Kase itoju iwa wa o
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato, kafi sile ma ma wu mo
Iwa ti towa leru ka di (Oti towa leru ka di o)
Kase itoju iwa wa (Kasetoju iwa wa)
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato
Kafi sile ma ma wu mo
Iwa longbeni niyi semo?
Iwa ma tun ni
Non fi nleni ni awujo iwa rere
Oun ma loye keda mawu toriwipe
Oun t'olowo kan ori ra towo toni
Tan ni ko fowo e sapo afi igberaga
Won felomiran laigbowo toriwipe
Iwa to dara t'iyen tiwu
Loje kon gbefun
Iwa toba ku kaato, kafi sile ma ma wumo
Iwa ti towa leru ka di
Kase itoju iwa wa o
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato, kafi sile ma ma wu mo
Iwa buruku kila o fiwe o kafi we íná
Ina tio r'enikan pa a ba'le je
A b'ode je bona je koni se kosi
Omi kekere ole pa koni fe kumo
Iwa toba wu toku káàto toba reni so
Tete gbe iwa ju sile koto wa lope
Oriyomi mowi temi
Owo e loku si ore wa
Iwa ti towa leru ka di
Kase itoju iwa wa o
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato, kafi sile ma ma wu mo
Alhaji monsuru loma nkorin kan o
Alhaji monsuru, hazza wa jalla
O latoke atile, t'olohun ni
At'omi ati ina t'olohun ni
At'aye atorun, t'olohun ni
Olohun fimimona kinma ba waye lasan
At'oke atile t'olohun ni
Olohun fimimona
Kinma ba waye lasan
S'obolohun to seda, oun ti af'ojuri
Omi okun boseto, iyanu ta f'oju ri
E tun wo bose seda, oun tao foju ri
Ati ategun atemi, oun tao fojuri
T'olohun bayo mejeji kuro lawa kowa
Kilemo ti yio sele, kama se raburu
Olohun f'iso e sowa kama ma pare maye
At'oke atile t'olohun ni
Olohun fimimona
Kinma ba waye lasan
Mo lenikan timo gbodo ki, leyan tose koko
K'olohun ma ma je a te, lowo arawa
Adewale ismaila komolafe
Baba amira ismaila komolafe
Adewale baba qowiyah, baba muhanmmad
Ooni t'ókó iroko d'óko irókotó
Ooni bawon wa nti o sonu kiri
Ooni bawon dasha pe koma s'owo mo
Itesiwaju lori dida oruko óré ati árá pelu ojulomo
Adewale ismalila komolafe
Silvergold entertainment
At'oke atile t'olohun ni
Olohun fimimona
Kinma ba waye lasan
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Didaruko oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Dida oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Dida oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Dida oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Naam
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Síse àlàyē isedaada onilenla simi
Ati oruko awon ebi pelu álábásepò
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Síse àlàyē isedaada onilenla simi
Ati oruko awon ebi pelu álábásepò
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Síse àlàyē isedaada onilenla simi
Ati oruko awon ebi pelu álábásepò
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Odi ile zanga
Zangaaa
Ajala o ro tote koto sore
Eluku o ro tegan koto shola
Eluku sope olohun lonse iyanu
Won nse kotan kotan olohun o jeo tan
Araba o wo mo, oju titi iroko
Tori nigbakan ri, ota tiro po le deyan
Ani nigba kanri, ota tiro poole deyan
Won fe ko teba tan, kowale won wa gbobe sini
Won fe koro amala tan, ko wale won wa gbobe sini
Won fe koro semo tan, ko wale won wa gbobe sini
Awon a fe karije, kama mayo leniyan
Afe karije kama mayo leniyan
Sungbon lasiko yi
Ola ti lae oju won lo
Oti wa ga j'ota lo
Oke ga j'oke
Itesiwaju ninu idaruko
Alhaji lukman shittu zangallo
Ati awon ebi pelu ore re
Oke gaa joke
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
Atesiwaju lori sise alaye nipa oloore wa
Alhaji rasheed agunwa
Pelu oruko awon ebi
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
Atesiwaju lori sise alaye nipa oloore wa
Alhaji rasheed agunwa
Pelu oruko awon ebi
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
A l'omo igbo kan ladugbo wa alaanu
Tonse f'onile se f'alejo ati opo
T'arugbo at'omidan
Tori bose nran won ni makkah
Lonran won ni umura, mashallah
Pelu saraa inu awe ti ramadan ba tinde
Aye l'omo barca chinma
Aayo waaaaa
Omo barca chinma
Eeyan waaa
Obama chinma
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Aiga nondirege
Nogenine ichorain
Aiga nondirege
Nogenine ichorain
Chineke iyenrege ego
Ogannafunge, anaha God
Aaaamiin
Obama chima
Wetin you dey do?
Na so so to give out
People dem dey pray, for your everlasting blessing
Wetin you dey like o
Na so so to give out
People dem dey pray, for your everlasting blessing
If many people wake o
In da early morning
Them dey always remember you in their prayer
If many people wake o
In the early morning
Them dey always remember you in their prayer
Ever before themselves o
Na you them dey mention
Ever before themselves
Na you be their hero
Before them do their prayers
Na you them dey mention
They say obama francis
Na you be their hero
Da king of our time
Obama omo barca
Da king of our time
Obama omo barca
Chima francis o
Na you we dey care for
Obama francis o
Na you we dey care for
No be money we you get o
Nain make me dey hail you
Na because you dey help
Nain make me greet you
No be money we you get o
Nain make me dey hail you
Na because you dey help
Nain make me greet you
Allahumma robbana
Atina fi duniya
Hassanatan, wafil akhirati
Hassanatan, waqina adzaba naar
Hassanatan, waqina adzaba naar
If you know the meaning
You go quickly say amen
Wetin i dey recite
You go always say amen
If you know the meaning
You go quickly say amen
Wetin i dey recite
You go always say amen
MashaaAllah
Oluwa lofi e se itanna wa
Komama ni so e sokunkun aye
Koma toshi koma dolareyin mubarokah
Oriyomi oni yanku funwa
Koma toshi koma dolareyin
Aye lowomo
Oriyomi oni yanku funwa
Dida oruko mubarokah tesiwaju
Pelu oruko awon ebi re
Yes!
Koma toshi koma dolareyin
Mubarokah
Oriyomi oni yanku funwa
Dida oruko mubarokah tesiwaju
Pelu oruko awon ebi re
Oh
Tor'oluwa lofi e se itanna wa
Komama ni so e sokunkun aye
Koma toshi koma dolareyin mubarokah
Oriyomi oni yanku funwa
Mo k'olatunde o
Saheed omo olayode o
Mo k'olatunde
Saheed omo olayode
Naam
Kosi igba timo ma pe e to kinje
Kosi igba timo ma pe e to kinje
Gbogbo igbakigba, toba polohun a je
Igbakigba toba polohun a je
Itesiwaju lori idaruko alhaji olayode olatunde
Pelu awon ebi re
Kosi igba timo ma pe e to kinje
Gbogbo igbakigba, toba polohun a je
Igbakigba toba polohun a je
Oh!
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Itesiwaju lori ìmenuba awon olola ghana bi:
Alhaji abdulahi bature ajao
Ati alhaji lateef olumegbon
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Itesiwaju lori ìmenuba awon olola ghana bi:
Alhaji abdulahi bature ajao
Ati alhaji lateef olumegbon
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Itesiwaju lori ìmenuba awon olola ghana bi:
Alhaji abdulahi bature ajao
Ati alhaji lateef olumegbon
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
A dupe oba yoruba ni accra
OBA hamzat peregrino braimo
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Ema siyemeji o
Won nfewa ni ghana gan ni
Ao siyemeji
Won nkewa ni ghana bi oju
Dida oruko awon omo egbe ti ajo lo si ghana
Won nfewa ni ghana gan ni
Won nkewa ni ghana bi oju
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Olohun lomo inu oyun iya ko towa aye
Olohun lomo inu oyun iya koto bi
B'omo waye b'omo naa ba tin gbon
Obi to bimo naa gbodo ma sho ni
Iya jade lo koto pada wa sile
Gbogbo oun to sele ki iya e o tode
Igba tode lomo nkà bi éyé fun
Toye koni komo naa o dake
Toba dagba koma pada wa túlé
Omo to njiwe ji biro egbe wale
T'obi omo o beere bose ri
Bon o tete mojuto ton kaju
Toba dagba to nféwó ebi won ni
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Otito lere bosewu ko peto
Tori pon leyin todun j'oyin lo
Se reni ti ab banse otito fun
Tonlo inu meji sini egun loje
Kanifura kama gbagbe ara wa
Tori alasiri ore kan o si rara, ifinu we'nu ma npada di íwó ni
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Mowa tewo s'olohun okansoso
Mo tewo s'olohun okansoso
Ma gba iwa mi tori ola aye lasan, òjò kù eda yi omi ágbádá nu
O gbagbe pe ojo leshu koma ro
Kinma fowomi serami laye
Kinma mu ika abami fi bo'nu
Gbami lagbatan allah maje nse
Asise tole mu alanu sa tan
F'ayo sinu aye mio kola o de
Eda waye eda gbagbe po ntan
Owo nikan leda ma nf'aye wa
Ife owo o gbodo lo tini pa
Ola aye o dorun afi aye lasan
Ema gbagbe atisun e se rere
Iwa ti towa leru ka di
Kase itoju iwa wa o
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato, kafi sile ma ma wu mo
Iwa ti towa leru ka di (Oti towa leru ka di o)
Kase itoju iwa wa (Kasetoju iwa wa)
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato
Kafi sile ma ma wu mo
Iwa longbeni niyi semo?
Iwa ma tun ni
Non fi nleni ni awujo iwa rere
Oun ma loye keda mawu toriwipe
Oun t'olowo kan ori ra towo toni
Tan ni ko fowo e sapo afi igberaga
Won felomiran laigbowo toriwipe
Iwa to dara t'iyen tiwu
Loje kon gbefun
Iwa toba ku kaato, kafi sile ma ma wumo
Iwa ti towa leru ka di
Kase itoju iwa wa o
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato, kafi sile ma ma wu mo
Iwa buruku kila o fiwe o kafi we íná
Ina tio r'enikan pa a ba'le je
A b'ode je bona je koni se kosi
Omi kekere ole pa koni fe kumo
Iwa toba wu toku káàto toba reni so
Tete gbe iwa ju sile koto wa lope
Oriyomi mowi temi
Owo e loku si ore wa
Iwa ti towa leru ka di
Kase itoju iwa wa o
Iwa to dara ka teramo o
Eyi toba ku káato, kafi sile ma ma wu mo
Alhaji monsuru loma nkorin kan o
Alhaji monsuru, hazza wa jalla
O latoke atile, t'olohun ni
At'omi ati ina t'olohun ni
At'aye atorun, t'olohun ni
Olohun fimimona kinma ba waye lasan
At'oke atile t'olohun ni
Olohun fimimona
Kinma ba waye lasan
S'obolohun to seda, oun ti af'ojuri
Omi okun boseto, iyanu ta f'oju ri
E tun wo bose seda, oun tao foju ri
Ati ategun atemi, oun tao fojuri
T'olohun bayo mejeji kuro lawa kowa
Kilemo ti yio sele, kama se raburu
Olohun f'iso e sowa kama ma pare maye
At'oke atile t'olohun ni
Olohun fimimona
Kinma ba waye lasan
Mo lenikan timo gbodo ki, leyan tose koko
K'olohun ma ma je a te, lowo arawa
Adewale ismaila komolafe
Baba amira ismaila komolafe
Adewale baba qowiyah, baba muhanmmad
Ooni t'ókó iroko d'óko irókotó
Ooni bawon wa nti o sonu kiri
Ooni bawon dasha pe koma s'owo mo
Itesiwaju lori dida oruko óré ati árá pelu ojulomo
Adewale ismalila komolafe
Silvergold entertainment
At'oke atile t'olohun ni
Olohun fimimona
Kinma ba waye lasan
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Didaruko oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Dida oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Dida oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Dida oruko ébi oloore mi
Pelu isedaada won simi ntesiwaju
Akanni balogun l'australia qomar
Abiodun oko jemila
Oba tofiyin kemi komani gbota laye
Konma fesu si arin awa
Naam
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Síse àlàyē isedaada onilenla simi
Ati oruko awon ebi pelu álábásepò
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Síse àlàyē isedaada onilenla simi
Ati oruko awon ebi pelu álábásepò
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Síse àlàyē isedaada onilenla simi
Ati oruko awon ebi pelu álábásepò
O gba iwaju yo o gbeyin yo onilenla
O durotimi o lo igbagbo, abiodun
O s'alatileyin mi, kofe kin rago
Ayinde nje kinma mope mo rile aye wa
Abi kini ka pe iru ife eyi na?
Odi ile zanga
Zangaaa
Ajala o ro tote koto sore
Eluku o ro tegan koto shola
Eluku sope olohun lonse iyanu
Won nse kotan kotan olohun o jeo tan
Araba o wo mo, oju titi iroko
Tori nigbakan ri, ota tiro po le deyan
Ani nigba kanri, ota tiro poole deyan
Won fe ko teba tan, kowale won wa gbobe sini
Won fe koro amala tan, ko wale won wa gbobe sini
Won fe koro semo tan, ko wale won wa gbobe sini
Awon a fe karije, kama mayo leniyan
Afe karije kama mayo leniyan
Sungbon lasiko yi
Ola ti lae oju won lo
Oti wa ga j'ota lo
Oke ga j'oke
Itesiwaju ninu idaruko
Alhaji lukman shittu zangallo
Ati awon ebi pelu ore re
Oke gaa joke
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
Atesiwaju lori sise alaye nipa oloore wa
Alhaji rasheed agunwa
Pelu oruko awon ebi
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
Atesiwaju lori sise alaye nipa oloore wa
Alhaji rasheed agunwa
Pelu oruko awon ebi
Oba toti nso bowa, maso poo somo
Ike to tinke bowa, ma ma lo kemo
Hajji rashidi agunwa bakare akanmu
A l'omo igbo kan ladugbo wa alaanu
Tonse f'onile se f'alejo ati opo
T'arugbo at'omidan
Tori bose nran won ni makkah
Lonran won ni umura, mashallah
Pelu saraa inu awe ti ramadan ba tinde
Aye l'omo barca chinma
Aayo waaaaa
Omo barca chinma
Eeyan waaa
Obama chinma
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Chineke geduwgi
Nainhonma imere nain
Aiga nondirege
Nogenine ichorain
Aiga nondirege
Nogenine ichorain
Chineke iyenrege ego
Ogannafunge, anaha God
Aaaamiin
Obama chima
Wetin you dey do?
Na so so to give out
People dem dey pray, for your everlasting blessing
Wetin you dey like o
Na so so to give out
People dem dey pray, for your everlasting blessing
If many people wake o
In da early morning
Them dey always remember you in their prayer
If many people wake o
In the early morning
Them dey always remember you in their prayer
Ever before themselves o
Na you them dey mention
Ever before themselves
Na you be their hero
Before them do their prayers
Na you them dey mention
They say obama francis
Na you be their hero
Da king of our time
Obama omo barca
Da king of our time
Obama omo barca
Chima francis o
Na you we dey care for
Obama francis o
Na you we dey care for
No be money we you get o
Nain make me dey hail you
Na because you dey help
Nain make me greet you
No be money we you get o
Nain make me dey hail you
Na because you dey help
Nain make me greet you
Allahumma robbana
Atina fi duniya
Hassanatan, wafil akhirati
Hassanatan, waqina adzaba naar
Hassanatan, waqina adzaba naar
If you know the meaning
You go quickly say amen
Wetin i dey recite
You go always say amen
If you know the meaning
You go quickly say amen
Wetin i dey recite
You go always say amen
MashaaAllah
Oluwa lofi e se itanna wa
Komama ni so e sokunkun aye
Koma toshi koma dolareyin mubarokah
Oriyomi oni yanku funwa
Koma toshi koma dolareyin
Aye lowomo
Oriyomi oni yanku funwa
Dida oruko mubarokah tesiwaju
Pelu oruko awon ebi re
Yes!
Koma toshi koma dolareyin
Mubarokah
Oriyomi oni yanku funwa
Dida oruko mubarokah tesiwaju
Pelu oruko awon ebi re
Oh
Tor'oluwa lofi e se itanna wa
Komama ni so e sokunkun aye
Koma toshi koma dolareyin mubarokah
Oriyomi oni yanku funwa
Mo k'olatunde o
Saheed omo olayode o
Mo k'olatunde
Saheed omo olayode
Naam
Kosi igba timo ma pe e to kinje
Kosi igba timo ma pe e to kinje
Gbogbo igbakigba, toba polohun a je
Igbakigba toba polohun a je
Itesiwaju lori idaruko alhaji olayode olatunde
Pelu awon ebi re
Kosi igba timo ma pe e to kinje
Gbogbo igbakigba, toba polohun a je
Igbakigba toba polohun a je
Oh!
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Itesiwaju lori ìmenuba awon olola ghana bi:
Alhaji abdulahi bature ajao
Ati alhaji lateef olumegbon
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Itesiwaju lori ìmenuba awon olola ghana bi:
Alhaji abdulahi bature ajao
Ati alhaji lateef olumegbon
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Itesiwaju lori ìmenuba awon olola ghana bi:
Alhaji abdulahi bature ajao
Ati alhaji lateef olumegbon
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
A dupe oba yoruba ni accra
OBA hamzat peregrino braimo
Won ma setoju wa ni ilu ghana
Ni irin ajo wa oteyi tunse larinrin o
A comfirm pawon ara ghana
Won nse tiwa, nise non ponwa le
Ema siyemeji o
Won nfewa ni ghana gan ni
Ao siyemeji
Won nkewa ni ghana bi oju
Dida oruko awon omo egbe ti ajo lo si ghana
Won nfewa ni ghana gan ni
Won nkewa ni ghana bi oju
Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.