Anu

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Kosi ohun ti mo le se
Lai si iranlowo re baba
Ayeraye ma wo mi niran
Jowo dasi oro aye mi
Ki anu re fohun
Ki gbogbo idawole
Mi ma yori si rere
Bi orun ba si fun mi
Ase irorun ohun lo ma tele
Adura a ma gba
Alubarika a wole ise a mu ere wa
Ire lotun ire losi
Laye eyan orin ope a tun yo

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Oro re fi yewa
Iwo yio sanu fun
Eniti iwo o sanu fun
Eyonu re yio wa
Lori eniti iwo ba yonu si
Laye ati ni orun
Baba jowo je nipin ninu eyonu re
Kin se nipa adura
Abi iwa mimo abi eto
Bikose nipa ore ofe ati orire
Aye mi nilo ore ofe ati orire
Lati odo re baba mi
Kanu re joba laye mi
Ati ohun gbogbo to jemo temi

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi

Silekun ayo mi
Baba silekun ayo mi
Ibanuje o jeko jina silemi
Wa mu inu mi dun
Baba onile ayo
Oro ayo mi
Ma jeko pamilekun
Silekun ayo mi
Baba silekun ayo mi
Ibanuje o jeko jina silemi
Wa mu inu mi dun
Baba onile ayo
Oro ayo mi
Ma jeko pamilekun
Silekun ayo mi
Baba silekun ayo mi
Ibanuje o jeko jina silemi
Wa mu inu mi dun
Baba onile ayo
Oro ayo mi
Ma jeko pamilekun

Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
Baba sanu mi
Ranmilowo Oluwa
Jeki Orun si fun mi
Kanu soro laye mi
Baba sanu mi



Credits
Writer(s): Awoyomi Oluwabukunmi Abraham
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link