Kosi (feat. Olori C.A. Ogunde)
Oluwa Olorun orun
Oruko re ti niyi to ni gbogbo aye
Ta la ba fi o we? Kosi
Nitori eyin nikan soso ni Olorun
Oga ogo julo, Oba ogo
Oluwa Olorun awon omo ogun
Oba to ju gbogbo oba lo
(Kabiyesi)
Kosi oba to dabi Olorun mi o (owun ni Olorun)
Kosi oba to dabi Olorun mi o (owun ni Olorun)
Laye lorun owun nikan loba (owun ni Olorun)
Ani laye lorun owun nikan loba ayeraye (owun ni Olorun)
Awon alagbara n beru re (owun ni Olorun)
Awon olori angeli won n' wole fun
Won n'wole fun
(Owun ni Olorun) kabiyesi re
Kosi oba to dabi Olorun mi o (owun ni Olorun)
Kosi oba to dabi Olorun mi o (owun ni Olorun)
Owun ni alagbara lorun ati ni aye (owun ni Olorun)
Alagbara aye kan o le woju re (owun ni Olorun)
Sebi owun lo da orun, Owun lo da aye (owun ni Olorun)
Ah, ohun to ba ti so dandan ni ko se o o (owun ni Olorun)
Nitori, kosi ohun to soro se fun
Kosi oba to dabi Olorun mi o o (owun ni Olorun)
Baba ese
Kosi oba to dabi Olorun mi o o (owun ni Olorun)
Laye lorun (owun ni Olorun)
Olorun otito (owun ni Olorun)
Mo so, mo tun (owun ni Olorun)
Olodo ododo (owun ni Olorun)
# instrumental

Credits
Writer(s): Adegboyega Adeoye Ogunde, Olori C.a. Ogunde
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.