Ayo N Bo

Ko si boti le wu
Ka le le to o
Ko si boti le wu
Ki iji ja to
Ko si boti le wu
Ko soro pe to o
Ko ma si boti le wu
Ki wahala Po to
(Ayo n bo)
Chorous
Ayo n bo
Wa o
(On bo wa)
Imole re tide
(Imole a tan)
Ayo n bo
(Ma soreti nu)
Wa o
Imole re tide
(Ayo n bo wa aaaa)
Ayo n bo
Wa o
Imole re tide
(Imole re tide)
Mo gbe gbogbo aniyan mi loluwa
(Loluwa)
Mo jowo re lese agbelebu
(Lese agbelebu)
Bekun pe dale kan
(Ayo)
Ayo n bo lo euro
Mo to ri imole
Mo ni ireti to daju
(Ayo to daju)
Ayo n bo
(I have the assurance)
Wa o
(Because I have Jesus)
Imole re tide
(Imole a tan)
Ayo n bo
(Ayo n bo wa aaaa)
Wa o
(Egungun gbigbe a di aye)
Imole re tide
(Imole)
(Ayo n bo wa)
Mo yo
(Emi Jo)
Mo Jo
Mo yo
Ola adara
(My tomorrow shall be great)



Credits
Writer(s): Florence Oladunjoye
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link