Alapomu

Beat instrumentalists
Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Apomu arire ajoba tuntun
Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Oh, ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Ori toti gbade e latorun, toba daye
Koni salai di kabiyesi o, yio joba
Ori tio joba yan ipin e latorun, koto waye
Akanni mosunmoba niwon egbefa oo

Mo jinna soba niwon egbeje
Lofi jepe, mowari f'ade mote f'oloye
Moti kore

Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Ooh oo
Oba atoyebi elekeji nio ooo
Oba atoyebi elekeji ni, oba tuntun
Timofi towotowo darukore ni
Oba alade, oban kayode adenekan mi
Oba alade

Alapomu tilu apomu, oba tuntun
Atoyebi elekeji nii, atoyebi elekeji ni
Oba tiwa, bese gor'oye gbogbo nkan tuntun, miringidin
Kilu tundara ju tateyinwa, kamakore

Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Ooh oo o
Tidera talafia pelenu ase, kope tan
K'irukere dokinni kobape, kadepe lori
Oba adenekan alapomu joba, aye ndunnu

Ibere ti juwe biose ma dunlo ooo
Ibere ti juwe biose madunlo, adupe o
Betie banja omo lonperire o, afolabi
Alapomu tilu apomu, oba ni
Isokan e gbera kajomayo nio, atikore

Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Oriyomi emi naa nba ilumi yoni, mofidupe
Ejire gegebi omobibi apomu
Gan-gan-gan
Iya tobimi omo ikire ni, ojulowo

Baba tobimi omo apomu ni, original
Tonba biyin pe nbo nile temi, l'apomu
Agbole oloode lagbole tawa loyekanbi

Timoba nperi kabiyesi tawa, mofekope
Omo ilu naa lonperi oba, motikore o
Isokan e gbera kajomayo ni, ebandarin

Apomu arire ajoba tuntun
Lomode lagba ndupe pa joba
Itesiwaju nba ilu apomu

Ilu nfeleyi dupe ire ayokan, pajoba tuntun
Isokan e gbera kajo mayo ni atikore

Apomu eje kajose ooo, eje kajose
Oju o gbodo toba tiwa, eje kagba fun
Oju o gbodo toba tiwa ebaje kajose Kodan

Eje kajose ooo, eje kajose
Oju o gbodo toba tiwa, eje kagba fun
Oju o gbodo toba tiwa ebaje kajose Kodan

Ibi tode lana kobaje afe o darasinio
Ibi tode lana kobaje afe o darasini
Ibi towa loni, afe ko nitesiwaju
Tio ba fidola, afe kaye ope mayo

Oba toje loni oo, oba toje loni oo
Oba toje loni, eje kagba fun
Gbogbo isokan lapapo ebaje kajose kodan

Eje kajose ooo, eje kajose
Oju o gbodo toba tiwa, eje kagba fun
Oju o gbodo toba tiwa ebaje kajose Kodan

Ede aiyede kankan komasele larin oba
Ede aiyede kankan komasele larin oba
Pelu oloye ilu o kajo fimowa sokan
Gege bi oruko todo tiwa tonpe nisokan

Kama dite oba, kasima sabosi oba
Kaf'oba laye koseto bilu sele dan o
Toroju o gbodo toba tiwa, eje kagbafun
Oju o gbodo toba tiwa eje kajose kodan

Apomu nilumi, mo yangan
Moyan fanda
Moyan fanda, mo yangan
Moyan fanda

Kabiyesi loni ndupe o
Mo yangan, moyan fanda
Fun tijoye t'ara ilu o
Mo yangan, moyan fanda

Apomu niluu mi
Mo yangan, moyan fanda
Apomu śūūru
Mo yangan, moyan fanda

Oko ilu bantu bantu
Mo yangan, moyan fanda

Omo aroworade lapo'le
Mo yangan, moyan fanda
Awa lomo Asunkungbade o
Mo yangan, moyan fanda

Omo ajiboshin omo odudu
Mo yangan, moyan fanda
Omo ogege omo alatee

Omo alate ajifowora o
Mo yangan, moyan fanda
Apomu nilumi
Mo yangan, moyan fanda



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link