Calypso

Eruku fe la molly
Ile fo illuminati
Awon temi nu trenches
Gboja Sara bi Gabi
Ibile mi le ti ti
Owo ti wole kisiii
Billion dollar la worthi
Awon cold kawa de ma hottie

Jeki n la e bi callypso
Jeki n ru n e bi gattuso
Jeki n ge e bi Ronaldo
Jeki n je e n be Eminado

Omoge onidi Rabata
Jeka wole kin wa lo da
Ki lo fe sebi na raba
Sedi dada ko wa lo gba
Awon temi taka sufe
Won gbo'olosho pelu 2k
Omo toba go ni ke mu
Eyi to ba sun ni ke run
Khalifa lomu shakira
Khalid lo run Rihanna
Emi ke mi o le da Saara
Mo ya tete lo b'adija
2+2=4
Omo to ba su n efooor

Jeki n la e bi callypso
Jeki n ru n e bi gattuso
Jeki n ge e bi Ronaldo
Jeki n je e n be Eminado

Won fe bami ke
Won ba mi ti
Ilefo lemi mo n ta won biti spiriti
Mo Kala biti kalamu
Dajupa biti dauda
Ma re rin koya pa data
Wuwa ika ma lo se transfer
Iwo kan noni gold digger
Iwo kan lo nje banana
Sugar daddy lo ma n bato
Awa niggaz la de ma ndo
Emi ti no ti n wa ti pe
Moya pot e si Waju biti commando
Jeki n la e bi callypso
Jeki n ru n e bi gattuso
Jeki n ge e bi Ronaldo
Jeki n je e n be Eminado



Credits
Writer(s): Toluwani Hamzat
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link