Ilara

A-udzu billahi mina shaetoni rojeem
Bismillahi rahmani roheem
Inna llaha yahmuru bil adli wal ihsaan

Waitaizil qurba wa yan-a anil fahshai wal-munkar
Wal-bagyi yaizukum la-lakum tazakkaruun
Sodaqa llahu maolanal azeem

T reign on the mix
Sole bimi ninu sha

Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai

Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Oriyomi, tori iwa ilara
Iwa kan tio da maloje
Eni banse ilara, kosi ki iru e ma sabosi

Awon onilara loye kiwon sima pe lesu
Ero gidi, koma si ninu okan won ri

Adua won
Won o lese laima fepe kun
Seronilara ko jinna sodomi aole re

Iwa ilara, iwa ilara
Koma ye lawujo atogba
Iwa ilara, komaye lawujo ategbe

Modupe iwa mi
Atawon ton komi mo gbeko o
Iwa ilara, kosi ninu iwa temi ni

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Eda onilara
Erokero nio ma ro lokan
B'eyan kan kole ton sadura pele atura o

Igba tio so, oni sele eyi le pe fun
Ile lagbaja
To ko bungalow sona mefa

Anyway
Ile atura na o sungbon sha
Se ile tenko

Tawon omo le gbeta teba ku
Poun eye baje, leye ma gbefo nitoun
Ile kiko, koje babara nitoun sha

Lenu onilara
Egbo onilara
Oje dake masoro yen mo
Iwa ilara, oma nbase omo eda je

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Haa!
Eda onilara
Orokoro nio ma solenu
Tobaje motor

Egbo oun tonilara eda awi
Ani kinigan, kini kini kini kinigan

Ani kinigan
Kilewa npewo teori ri
Erorayin pin, setori venza t'ajadi ra

Elowo enikan, range rover 2017
Oun lenikan ra
Koseyi tole joun loju

Tori polowo ooo
Tori polowo fowo raku maloko yen je
Owo tan o mana konije ki eda le sinmi

Egbo onilara, sengbo onilara
Koni ro poun gan male ra
Aforo odi

Nioma jabo lenu e ni sha
Iwa ilara
Ha! Iwa ilara, kosi ninu iwa temi lailai

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Ooh oo, ooh o
Oniwa ilara yio mafe kojoun nikan ni
Kiife kenikan

Niru oun toun ba jaja ni
Afemi afemi
Loma nsonilara eda aye

Tenikan ba niun toje ponilara o loni
Bi kobaje kawon maje ni nkan oun ni
Agaga kojepe
Ore loni toun o bani

Ani toripe, wonle ma bu oun wipe
Oun sisesise
Oun o niru nkan toreni
Iwa ilara

Toba niru e kofi bu
Pe k'olohun yo
Pe k'olohun yo
Tori onbase owo edaje

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Onilara eyaaaaaaan o
Onilara eyan o, koni rope koun ledupe
Nitoriwipe

Konitelorun ri af'owu
Oun to bani
Kopo lojue ri kole to

Aayo okan
Kole niru e o kofe ni
Oun toba ni
Kole wu bi oun tenikan ni
Kosekose, kotun nife konire ose

Koni gbegbese
Tojupe ki nkan lebaje
Beronilara, beronilara
Eba nwi fun kolo mo wipe
Omi teda o muuu

Ha!
Omi teda o mu, koni koja enu re laye
Gege bi ati ko oooo
Gege bi atiko
Bee nile aye eda nri

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Ha! Seronilara, kolefe konbaun taja kan naa
Toba joun ni, to koko riiso si ayekan
K'elomi deee
Kelomii de towalo jeru oja kan ni

Seronilara, akoko yomo iru eyan bee
Asope e wo, kape mejo koni kama ta o
A l'oju orun

Aloju orun, teye e fo lai kolura
Iro lonpa, eje konitoun bere na
Ikanra ni, ikanra ni

Abi kosope toun nsa soun
Ti customer bade o

Ti onibara bade
Tonba nnaja lowo onilara, tio ni lori igba

Konilori igba mo, koniso penikeji oun ni
Toye ko so powa, ko dogbon ra lowo enikeji
Ooonilaraaa aa
Onilarara, koniseru iyen o rara

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Abe rolowo kan toni dukia o repete
Ki lotun nwa
Nibi wipe koma selara
Adugbo towaaa o

Adugbo towa
Kofe kiru oun tun simo

Ayalegbe e lora gulf two nibi tongbe o
Lobanselara ayalegbe e o seraye
Oni kolowa, ibikan tole gboko yen si

Oni tobaya
Yiofe maba oun du ase ni
Iwa ilaraa

Iwa ilara, kenimani omo eniyan
Ojelo jawo, kosere kan nibi ilara
Iwa ilara kosi ninu iwa temini (modupe)

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Ha
Enikan loso
Wipe oun mani ore kan
Tawon jo kawe, awon jopari nigbakan ni
Oun o rise, ore oun nikan lorise

Yio fun unlowo, ha a foun lowo
Atounje beni pelaso
Oni timotimo

Lawon wa tiosi ija kankan
Owa digbakan lore oun ba bere sinise

Onse gbonku gbonku
Gbonku gbonku
Kotie femari oun mo
Ase toripe oun tirise toun tinwa o

Tiwon nsan ilopo
Meji owo osu tongba
Iyen lofa ilara, iyen lofa ilara

Ofe koje oun nikan ni
Koma rowo yo, kenikeji o dabi eru
Kosaun kosife wipe kenikeji orise

Yoruba fisope
Oro yorubaa
Ara'le eni, tio fe kaku, kosife ka jeniyan laye
Owo afunni tie nikan lofe kowa loke

Nisale ni, lofe ki tenikeji o gbe
Yee selara, ore maselara
Oma nbase owo edaje

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Konko jabele
Ki kaluku sima se tie
Lowe onilara, lomanso lenu nigbagbogbo
Onilara, kolese lai dote sile

Boys quarter, lonilara ngbe o seraye
Atojule ateyinkule loti sabosi
Yio gbo teku loso f'eye pelu abosi
O ri ara ile eee, oori ara ile e

Tora plastma sooripe
Tokunbo lora
Kilomu tiole ra tuntun?
Agbanaa, agbanaa

Igbawo nio fibaje na? Onilara
Oje jawo mawuwa yimo
Iwa ilara, ole base owo edaje

Sole bimi ninu sha
Kole bimi ninu lai
Oriire eda egbe mi koba ninu je o
Iwa ilara kosi ninu iwa temi ni

Seriki owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun

Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse afese fee

Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan

Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Awon atenu owo epo ooo
Atenu owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun

Owe agba ni bonile jeun tan, huun
Won a fowo nuri, balejo jeun tan, heen
Won afowo nuse won afesee (awon atenu)

Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan
Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Madiba toba dafun e toribatise, huun!
Oun laye aso wipe kokalo
Heen

Sowari kalo onitumo gan, huun
Ti won banisoro tojenu ebi, heen

Won ani kokalo kowalo bawon gbo
Huun
Tonba nisoro tagba won o ka, heen

Won atun ni kokalo kowalo bawon gbo, huun

Gbogbo oun tole tagbara won o gbe, heen
Won ani kokalo kowalo bawon gbe, huun

Ibi totidun loma riwon si, heen
Ibi tonti nta motor igbalode, huun

Won ani kokalo moma mobikan, heen
Ataso ati bata topoju owo, huun
Ninu motor towa koto tun bole, heen
Won ati shilekun koto looshi, huun

Atenu owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun

Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse afese fee
Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun

Owe agba ni bonile jeun tan
Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Bee
Olowo jeun ku wonti sare gbe, huun
O ranwon nise won tun yowo ku, heen
Oro enu won tiwon tunso, huun

Peku tio ba pae awon ni kopa o, heen
Arun tioba se e awon ni komu, huun
Bose bo bata wonti sare ko o, heen

Won ni bukata oti sare gbo, huun
Arawon o da oti sarelo, heen
O saduroti o nawo nara o, huun

Iba typhoid lasan lomu e, heen
Eebi ojo kan won o le bae ko, huun

Atenu owo epo ooo
Awon atenu owo epo lomo araye nbanila

Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun

Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse won afese (owo epo)
Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun

Owe agba ni bonile jeun tan
Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Omoge arewa kan gbogbo aye fe fe o, huun
Ebi totiwa won tun jologo o, heen
Iwo loripe iwo logba fun, huun
Iwo lorife iwo lofi s'oko o, heen

Ojojumo ni kiki i love you, huun
Nitojo terun oun lomanso o, heen
Party osose lejo manlo o, huun

Sebi ese kan l'okada logba, heen
Ese basan tan ikan ga jukan lo o, huun
Oomu rode mo tori aleebu, heen

Konmama pe e loko elese kan o, huun
Tiosi ribe teletele ri, heen
For better for worse de loye koje o (huun) koye koje owo epo

Tomo araye nbanila
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun

Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse afese fee
Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun

Owe agba ni bonile jeun tan
Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Iwo ri fine boy o sare bemo, huun
Handsome guy owa ndinju si, heen

Koti pe e oti nawo saya o
Huun (pe semi)
Koti soro oti sare lo o, heen

O ni bawoni osope mogbo, huun
O ni sewapa o sope mogba, heen
Kiloun tobie kilofi nje, huun

Toriponi motor o sare wose o, heen
I love you lo nfojojumo so, huun
Igba toda pau bobo o lowo mo, heen
Owo ounje ose kan kori fisile, huun

Torosafere korase pamo, heen
Koposu mefa oti kerulo, huun
Atenu owo epo ooo
Owo epo lomo araye nbanila

Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun
Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse won afese (owo epo)

Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan
Afowo nuri, balejo jeun tan

Af'owo nuse afese fee
Iyawo asese gbe aribanije o, huun
Iwo se party gbogbo aye peju, heen

Won tun tete de won nawo nara, huun
Gbogbo awon alfa won rowo mulo, heen

Owo kurani tiwon da fomo, huun
O po debipe iyen buaya, heen
Ode kan enikan totun sunmo e, huun
Oowa tetede kotodi pode, heen

Oti nsare pe, sawon alfa tilo, huun
Igba tonro amala tan lowa yojude o, heen
Semo dele tan lowa yo sibe o, huun

Atenu owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun

Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse afese fee
Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun

Owe agba ni bonile jeun tan
Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Iyawo
Egbon oko tie malowa kie, huun
O sare sebe oti gunyan fun, heen

Miliki meji pelu maltina kan, huun
Loko siwaju wipe kofi lo, heen
Tori toba nlo a fun e lowo, huun

Koi fowo sapo o sare kunle, heen
Bose fikunle be otun ti tewo, huun
Owo ojo kan tio ri fun e, heen

Igba tio padawa o bere kinio je o, huun
Pure water kan logbe siwaju re, heen
Atenu owo epo ooooo loje o

Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun
Owe agba ni bonile jeun tan, huun

Afowo nuri, balejo jeun tan, heen
Af'owo nuse afese eeraye
Owo epo lomo araye nbani la
Aye o le banitan isoro a f'olohun

Owe agba ni bonile jeun tan
Won afowo nuri, balejo jeun tan
Won a f'owo nuse afese fee

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Adua mi atawe mi saraa mi ti gbaa
Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba oo

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Olohun mi ole gbagbe aniyan timo da o
Eyi timole sojade ateyi tojepe
Inu okan mi malowa
Olohun mi timo

Tolohun bale se yanju
Inu mi maa dun, madupe ope oniletan
Ma du pepe okun mo

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Oooo-nafila mi ataisun mi
Olohun mi tigba
Nafila mi atawe mi, olohun mi tigba
Saraa mi o ja sasan, o funmilesi ayo

Kosi bosewu kokun to
Otun ku timo fe
Ibi tokusi yah robbi

Wa bami so daayo
Otale ati tode kiwon le foh ela
Kiwon le foh elalala
Kiwon lefoh bi igba o

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Ha, adua mi omale ha, kole ha o
Adua mi omale ha
Olohun lonseeto, ile ase malo kosi
Mo nireti aayo
Tebi tara tojulumo

Won nbo wa bami yo
Ijo adun ijo ope, pelu erin ayo
Otale ati tode kiwon le foh
Otale ati tode, kiwon le foh bi awo

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Ile totidun obare
Koma daru allah, haaun!
Ile totidun obare
Koma daru allah
Ki toko taya lewa dale, kon nibugbe ayo

Olohun ma farun sewon
Ma dawon s'adanwo
Oriire ase dale, fi sorowon allah
Kotale ati tode
Mofe kon foh bi igba o

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Oriyomi, mo f'okiki ati owo
Pelu emi gigun
Ninu erin ati ibukun, ninu alafia o
Pa alo ati abo mi mo
Kinma se rewu ona o

Kile mi mase gbona
Ko tutu bi omi amu
Adua mi ateyinwa
Jeko gba mo tile o
Kotale ati tode kiwon le foh bi igba

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Omo malaa sotami d'afopina, tofe fe fitila pa
Kota ode ati tile fowo e sera e o
Amoni seni ati asenitan
To tun nbani daro

Je kon saseti lorimi, doju tiwon allah
Kotale ati tode kiwon lefoh ela
Kiwon le foh elalala
Kiwon lefoh bi igba

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Oremi o kilofe k'olohun Allah ose
Dunnimo adua komase

Masoreti e nu, kosi boro eda sepe
A de ebute ayo
Ore aye e ti sunmo adua e tigba

Otale ati tode, o sure
Otale ati tode, niwon mafoh bi awo

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Alao, ise toba le fakoba
Konma pewa sibe o
Ode lilo aini dari, kama rin lona ibe o

Ile njo ole nja kamari laye awa o
Olohun ma soluso wa
Kama se r'agbako o
Otale ati tode kiwon le foh bi igba

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba

Ewo, badoo ni tikorodu ton ndemi legbodo
Boko haram ti north

Tiwon nfemi sofo o
Oba yah robbi je o dopin wa bawa segun re o

Ti ibinu re o lobaje darijinwa allah
Ah tibinu re o lobaje darijinwa allah

Wola awon odomode
Tiwon je alaise o
Sanuwon nikorodu ati nibikibi allah

Adua mi atawemi saraa mi tigba
Olohun mi tete shola kotami legba o
Ota ile ati tode mofe konfo bi igba
T reign on the mix



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link