Oluwa Lagbara Mi

Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Mori Oluwa niwaju mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo otun mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo osi mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa niwaju ogun
Mo wo eyin o wa nibe
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota

Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Mori Oluwa niwaju mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo otun mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo osi mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa niwaju ogun
Mo wo eyin o wa nibe
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota

Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Mori Oluwa niwaju mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo otun mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo osi mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa niwaju ogun
Mo wo eyin o wa nibe
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota

Jesu ni balogun oko
E ma se je ka foya
Olutoko wa ni Jesu
Yio mu oko wa gunle
E ma se beru
E kun fun ayo
Nitori Jesu loga oko
Bo ti wu ki iji naa le to
Yio mu oko wa gunle
Eyin ero to wa n'u oko
E kepe Jesu nikan
Ki esi gbeke yin le Jesu
Yio mu oko wa gunle
E ma se beru
E kun fun ayo
Nitori Jesu loga oko
Bo ti wu ki iji naa le to
Yio mu oko wa gunle
E ma se beru
E kun fun ayo
Nitori Jesu loga oko
Bo ti wu ki iji naa le to
Yio mu oko wa gunle

Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Mori Oluwa niwaju mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo otun mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo osi mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa niwaju ogun
Mo wo eyin o wa nibe
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota

Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota
Mori Oluwa niwaju mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo otun mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa lowo osi mi
Mo wo eyin o wa nibe
O wa niwaju ogun
Mo wo eyin o wa nibe
Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota

Oluwa lagbara mi
Emi ki yo beru ota



Credits
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link