Ope Loye O

Ọpẹ lo yẹ ọ, Baba olore
Eyin ma l'ọlọrun ọba
Iyin lo yẹ ọ, Baba olore

You are my rock, my shield and shelter (yessir)
I call You Lord, Father and Master (yessir)
With You by my side nothing else can matter (yessir)
I call You (Oluwa)
I call you (atobiju)

You are the reason for the sun in the sky (yessir)
Atobajaye, gbongbo Idile Jesse (yessir)
First Born of the most High God (yessir)
The Alpha (yessir)
The Omega (yessir)
Lift your voice and praise Him

Opẹ loyẹ ọ, Baba olore
He deserves the praise, He deserves the glory, He deserves it all (ẹyin ma l'ọlọrun Ọba)
Eleruniyin Oba nla (Iyin loyẹ ọ, Baba olore)
You alone will I serve titi lailai, titi lailai

Who can bring me restoration (only you)
Who can give me the wealth of nation (only you)
Who can turn my sorrow into dancing (only you)
Only you (only you), say only you (only you)

Tell me who can make the blind man see (only you)
Tell me who can open the red sea (only you)
Tell me who can bear the name Jehovah (only you)
Tsikenu (only you), Elianah (only you)

Tani ma f'ọpẹ fun (Ọpẹ lo yẹ ọ, Baba olore)
Alagbada ina, alawọ tẹlẹ orun
(Eyin ma l'ọlọrun ọba) yes you are
Iyin lo yẹ ọ, Baba olore (you deserve the glory)

Ta la ba f'ọpẹ fun afi eledumare oba (only you)
(Ọpẹ lo yẹ ọ, Baba olore) ọgbà gba tin gba alailara
Ọba a fini m'ọna, ọba m'ọna fi ni o (ẹyin ma l'ọlọrun ọba)
Atẹrẹrẹkariaye (Iyin lo yẹ ọ, Baba olore) baba mi o

Mo ju ba re ọba àwọn ọba, Kinihun ẹyà Juda
I'm alive because of you, eh
Where would I be without you Lord

Eyin l'ọba ti jẹ emi ni o (emi ni, emi ni)
Mimọ, mimọ, mimọ olu ọrun o (emi ni, emi ni)
Ma jọba lọ, kabiyesi ma jọba lọ (emi ni, emi ni)
Mo juba re Oluorun (emi ni, emi ni)

Kabiosi o laye at'ọrun o (emi ni, emi ni)
Ọba nla ti ẹda kan o le ba ja (emi ni, emi ni)
Tani to ọ lagbara, tani to ọ ni imọ (emi ni, emi ni)
Laye at'ọrun ko ma si, ko ma si rara (emi ni, emi ni)

Reign forever king of creation



Credits
Writer(s): Akinwunmi Akiremi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link