Halleluyah

O fun mi lee di di eee
Gbe se nla ti mo je ohoh
O si fun mi
O si re rin oh oh
Pe ma a she gbagbe mi

HE give to me a seal yeh
Of the debt i own
And as he gave
He smile and said
Always remember me

Halleluyah ooh
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo
Halleluyah
Awon Angeli nko mimo mimo
Halleluyah ooh
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo oh

Mo wo mo si re rin
Mo tun mo so kun
Eri ife re si mi ni mo
To ju ree titi

Halleluyah ooh
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo
Halleluyah oooh
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo (halleluyah)
Halleluyah
Awon angeli nko mimo mimo oh



Credits
Writer(s): Tolu Ajayi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link