Mofori bale (feat. Peculiar Emmanuel)

Mofori
Mofori bale
Fun Jesu Kristi

Mofori
Mofori bale
Fun Jesu Oba

Mofori bale
Fun Oluwa
Oba awon oba

Oba awon oba
Oluwa awon oluwa

Oba ti ko yi pada
Ogo ni fun oruko re

Mofori bale
Fun Oluwa
Oba ogo

Mofori bale
Fun Oluwa
Oba mimo



Credits
Writer(s): David William-adusa
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link