Olorun Elijah

Ina saju oluwa o si jo awon ota re run
Ina Oluwa a pe o oh
Wa pa gbogbo ise esu run
Mo ni Ina saju oluwa o si jo awon ota re run
Ina Oluwa a pe o oh
Wa pa gbogbo ise esu run
Olorun Elijah oba to fi ina daun
Olorun Elijah olorun alagbara
Olorun Elijah wa jeri ara re
Wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Olorun Elijah oba to fi ina daun
Olorun Elijah olorun alagbara
Olorun Elijah wa jeri ara re
Wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Ina saju oluwa o si jo awon ota re run
Ta ni iwo oke ni waju zerubabeli o di dan dan ko di petele
Nitori olorun mi be li aye
Oba to fi ina da Eliajh lohun ni waju orisa babeli
Iyen loje ki awon aborisa mo aye won ni ojo yen
Baba mi sora re ji
Oya ru re soke ki awon alagbara okunkun le mọ aye won
Aaah olorun mi fi titobi re han
Aaah olorun mi fi titobi re han
Gbogbo ona ti aye ni oti tan fun mi
Gbogbo ona ti aye ni oti di mon mi
Won ni ko si ona abayo won ni ibo ni ma gbe gba
Apanla to la ona ninu okun oya fi titobi re han ko ogo re buyo
Alagbara wa fi titobi re han
Ayeraye wa bu ja de
Oba to la ona ti bi ona o si
Baba wa lana abayo
Ja ja ja ina olorun oya ja
Gbogbo ide ti aye fi n de ire mi
Gbogbo ide ti aye fi n de ogo mi
Ina olorun mo pe o oo oya ja ki majemu se
Ina olorun mo pe o oo oya ja
Olorun aye raye fi titobi e han
A sa ti fi ami ororo yan oo lati tu awon igbekun sile
Ina Olorun mo pe oo oya ja gbogbo ide inu aye mi
Nitori oro oluwa lo wi pe e tu ketekete sile nitori oluwa ni fi se
Oya ina olorun mo ra o ni se jah gbogbo ide aye mi danu
Nitori oluwa ni fi mi se
Ja ja ja ina olorun oya ja ki gbogbo ide ai aṣeyọri
Ide ai tesiwaju oya ma ja lori ko Jesu
Agbara to tu Paul and silas sile oya ja
Agbara to tu Samson sile ninu ide oya ja emi mimo olorun ja
Olorun Elijah oba to fi ina daun
Olorun Elijah olorun Alagbara Olorun Elijah wa jeri ara re
Wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Lori ile mi fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Ninu ijo wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Lori ise wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Lori eko wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Lori eto isuna wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba
Lori ilera wa fi titobi re han kaye le ma pe iwo nikan ni oba



Credits
Writer(s): Odedeji Bimbo Elizabeth
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link