Gratitude
Odin-din ọmọ (odin-din ọmọ)
Uh-uh-uh
Wicked (allow)
Wo, so many things wey don sup (sup), iron wey don rust (allow)
People wey don kpeme, body wey don rot
Jẹjẹ ní mọ ṣáyé, miofe báwọn k'aba mọ (wo, wo, wo)
Mode bẹ'rù àyé tótó, ọmọ ẹ'dá adamọ
See, I dey work, I dey pray, all my giants I dey slay (slay)
Tàn imole sáyé mí, I don't wanna go astray
Make my hustle pay (pay), k'ogun àyémi fail (fail)
K'ìjì ma jamí, kí ńmá ṣe r'ogun hurricane (allow)
Bàbá l'òkè, jọ'wọ', ṣ'Ami s'àdúrà mí (s'àdúrà mí)
Funmi ní Ferrari, k'owá bámi m'Acura mí (m'Acura mí)
Funmi lágbára, májẹ kó remi (allow)
Ma jẹk'àiyé yemi, má jẹk'ojú timí (wo, wo, wo)
Uh, e don dey tay wey I don dey ask You (ask you)
For the money, kinle ball bi Lukaku (bi Lukaku)
Uh, and I know say You go run am (allow)
'Cause for me to be broke is a taboo
Me, I no pray make person own spoil oh
Say my own e no fit spoil oh
Make my metal no rust, make dem no find me oh
Ki mummy mi jèrè mí oh
Daddy ti ṣ'àdúrà fún mí oh
Wípé mámálo, mámábo oh
Ńkan òní tabala mí lésẹ, oh na, bala mí lésẹ oh
Ṣebi you talk say I no go beg for food
Òun t'ẹnu májẹ, o tí dá látìgbà t'oti dàmi
Má fimisilẹ Bàbá, no way, no way, no way, no way
Ma fimisilẹ Bàbá, no way, no way
Bámi ṣ'Ami ṣ'àdúrà mí, bí mọ ṣe ń hustle (bí mọ ṣe ń hustle)
F'ìdáhùn sí ìbe'rẹ' mí, bí mọ ṣe ń rọju (ṣe ń rọju)
Jẹ'kí irawo mí tàn, k'ọmọ yìn bubble (allow)
Adùn niko gbẹ̀yìn ẹ, bí mo ṣe ń struggle (Jésù)
'Cause, 'cause nkan yapa t'ojú ri
Motí kò iyepe filling, mo déti ṣ'alàgbàfo rí (ṣ'alàgbàfo rí)
Uh, modupẹ torí Ìwọ l'alàgbàwí (allow, allow)
You're the reason for my riches, Ìwọ l'oṣe rábà yii
Ọmọ gutter di onílé, d'onílé odi olọ'nà (di olọ'nà)
Owó ní mo wa, mò pàdé ọla, àti iyì l'ọ'nà
Eyán Tope Alabi, ore mí o common
Mu lamba sílè kàn mo, gbọ l'àiyé dé Aljana (wo, wo, wo)
God, I wanna thank You for Your blessings (for Your blessings)
For the ups and downs, for the lessons (for the lessons)
Ogun àyémi létí ṣẹ ńsìn (otí ṣẹ ńsìn)
Ẹni p'orímí níbí o má tẹsi
Me, I no pray make person own spoil oh
Say my own e no fit spoil oh
Make my metal no rust, make dem no find me oh
Kí mummy mí jèrè mí oh
Daddy ti ṣ'àdúrà fún mí oh
Wípé mámálo, mámábo oh
Ńkan òní tabala mí lésẹ, oh na, bala mí lésẹ oh
Shebi you talk say I no go beg for food
Òun t'enu májẹ, o tí dá látìgbà t'oti dàmi
Má fimisilẹ Bàbá, no way, no way, no way, no way
Má fimisilẹ Bàbá, no way, no way
Wozzy (wozzy)
Wicked
(Spyritmyx)

Credits
Writer(s): Superwozzy Superwozzy
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.