Muje
Uuh-uh-uh-uh-uuh-uuh na, heehe-heehe-heeh
Sọlè mújẹ? (Heee-he)
Monipe tó bà sọrọ kékeré fún ẹ, sọmá lé mújẹ?
Olọgbọ'n tó ńṣe bí òmùgọ̀, òní bó ṣe jẹ
Ọrọ lásán là sọ fún òmùgọ̀, tí kò gbọn yẹn
Àjo má lówó yí ní, kòjẹ bóbá ṣe jẹ
Tóbá dè ńtí ńrí bẹ'ṣéfẹ, káṣá má dúpẹ'
Ńkán t'Ọlọrun mí bà fọwọ sí, ele bàjẹ́ o
Àdúrà tó jú gan-gan ní kí tiwá máṣe bàjẹ́ o
Gbogbo ẹyin tẹ ńfẹ'ràn mí, tiwá òle bàjẹ́ oh-oh, eh-eh
If you no get money, dem go take you play
Abi you think na one night work to get money like Dangote
You go tey oo, láì-láì, you go tey oo, wá pẹ níbẹ'
You go get brain when you don get white bear-bear
Ẹ'mí òní tàn 'ramí o, má kúkú ṣíṣẹ
Àtẹ́lẹwọ́ ẹni, kò kín tání jẹ'
Ẹ'mí òní gọ 'ramí o, má kúkú ṣíṣẹ p'owó
Àtẹ́lẹwọ́ ẹní, kò kín tání jẹ'
Jẹjẹ, jẹjẹ, ṣá láyé gbà
Jẹjẹ lólè ṣe o
Jẹjẹ láyé gbà
Jẹjẹ, ye
Jẹjẹ, jẹjẹ ṣá láyé gbà
Jẹjẹ lólè ṣé o
Jẹjẹ láyé gbà, jẹjẹ
Monipe tó bá sọrọ kékeré fún ẹ, sọmá lé mújẹ?
Ọlọgbọ'n tó ńṣé bí òmùgọ̀ òní bo ṣé jẹ'
Ọrọ lásán là sọ fún òmùgọ̀ tí kó gbọn yẹn
Àjo má lówó yí ní kojẹ bóbá ṣejẹ'
Bóbá dẹ ńtí ńrí bẹ'ṣefẹ, káṣá má dúpẹ'
Ńkán t'Ọlọrun mí bà f'ọwọ sí, ele bàjẹ́ o
Àdúrà tó jú gan-gan ní kí tiwá máṣe bàjẹ́ o
Gbogbo ẹyín tẹ ńfẹ'ràn mí, tiwá òle bàjẹ́, oh-oh, eh-eh
Ẹ'mí òní tán 'ramí o, mà kúkú ṣíṣẹ
Àtẹ́lẹwọ́ ẹní, kò kín tàní jẹ
Ẹ'mí òní gọ 'ra mí o, má kúkú ṣíṣẹ p'owó
Àtẹ́lẹwọ́ ẹní, kò kín tàní jẹ
Tóbá dẹ ńtí ńrí be' ṣefẹ', káṣá má dúpẹ'
Ńkán t'Ọlọrun mí bá f'ọwọ sí, èlé bàjẹ́ o
Àdúrà tó jú gan-gan ní kí tiwá máṣe bàjẹ́ o (it's STG)
Gbogbo ẹyín tẹ' ńfẹ'ràn mí, tiwá òle bàjẹ́, oh-oh, eh-eh

Credits
Writer(s): Aramide Babalola, Barry Jhay
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.