Ka To Sun, Olugbala Wa

K'a to sun, Olugbala wa
Fun wa n' ibukun ale
A jewo ese wa fun O
Iwo l'o le gba wa la
Bi ile tile su dudu
Okun ko le se wa mo
Iwo Eniti ki s'are
Nso awon enia Re

B' iparun tile yi wa ka
Ti ofa nfo wa koja
Awon angeli yi wa ka
Awa o wa lailewu
Sugbon b' iku ba ji wa pa
T' ibusun wa d' iboji
Je k' ile mo wa s' odo Re
L' ayo at' Alafia

Ni irele, a f' ara wa
Sabe abo Re, Baba
Jesu, 'Wo t'o sun bi awa
Se orun wa bi Tire
Emi Mimo, rado bo wa
So wa l' okunkun oru
Tit' awa o fi ri ojo
Imole ayeraye



Credits
Writer(s): James Edmeston
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link