Itan Mi My Story

Sha rara re, sha rara re, sha rara re ra!

Wa na brother, se ki n'so itan mi fun e ni
Duro na sister, se ki n'so itan mi fun e ni

Emi ati itan mi, itan mi nigba iya, bi Oluwa ti nbe!

Ha oh my God!
Se o mo ibi timo tiwa, ki n to debi ti mode
Koo to ma Dami lejo, so Fe gbo itan mi ni?

Emi ati itan mi, itan mi nigba iya bi Oluwa ti nbe

Oooo

Emi ati itan mi, itan mi nigba iya bi Oluwa ti nbe

Duro na, Emi pelu itan mi, itan mi nigba iya bi Oluwa ti nbe
Kato rohun ta ma e, oju ri, Gbona Kato raso wo oju ri
Ota wa nsebi ore, ore wa n sebi ota, emi pelu itan mi
Itan mi ni igba iya bi Oluwa ti nbe

Emi ati itan mi itan mi nigba iya bi Oluwa ti nbe

Mo rowo ogun, mo rowo ogun, Olorun ni o je keyin mo, pe emi rowo ogun

Emi ati itan mi itan mi nigba iya bi Oluwa

Se o mo Ohun ti mola koja, Koo to ma dami lejo
Koo to ma dami lejo, se o mo ohun ti'mo lakoja
Koto soro mi Lai da,se ki n ni korin bimo se Rin?
So le jiya timo je, se o mo Ohun oju mi ri to?
So ara re, wo!so ara re, brother so ra re, so ara re
Itan mi ni igba osi, bi Oluwa ti nbe

Emi ati itan mi, itan mi nigba iya bi Oluwa ti nbe

Oooo

Emi ati itan mi, itan mi nigba iya bi Oluwa ti nbe

Ti n'ba sofun e pe, mori owo ogun, se kin sofun e bose je

Emi ati itan mi itan mi nigba iya bi Oluwa

Gbona, lojo ojo kan, mo nlo lati lo wa ohun ri un o je so enu mi
Kebi o tie siwo koyee pami mo, kin tie siwo iya jije bi eni jeun
Mo gbadura pe kogun se, koma Jami, koma ja omo mi
Kin to wa laju pere, emi ri Olorun ogba mi lowo ogun
Orin mi wadi majemu, odi ase, odi imule, odi oro gboin gboin
Ase to Gbe Ile aye mi duro o, Ogun Jami, iji fe, oju mi ri to
Sugbon pari pari oro yi hallelujah moyege

Emi ati itan mi itan mi nigba iya bi Oluwa

Emi pelu itan mi

Emi ati itan mi itan mi nigba iya bi Oluwa



Credits
Writer(s): Temitope Arowolo Oluwasegun.
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link