Omo Ologo

Chechdaproducer (Chechdaproducer)
So

Uh, 'til the second coming of Jesus Christ, I go dey give them
Mu t'ajero from Monday to Friday, j'aye ni weekend
I no need up to 16 bars to prove that I am wicked
And, I bet y'all, can testify that this young nigga is gifted
O ya wọn lẹnu bi mo ṣe n tana tosh 17 to 19
"Best New Act," AFRIMA, l'aba gb'ori wọ quarantine
Lockdown fẹ run wa down, l'aba fariga, f'araki
Ki lọ ma gain ti n ba fall?
Tẹ ba ri ọta mi, ẹ ba mi bi

Kuronbẹ, lamba yapa, Ọlọhun n gbọ, wallai-tallai (wallai-tallai)
And God dey bless me too much, me, I no deny (me, I no deny)
And that's why they all chasing when I'm driving by (skrr-skrr)
I pray make my Samson no ever meet Delilah

Say, symbol of hope, for their eye, e be like soap
Wọn fẹ ki n ma f'aya wọ bi crocodile, aṣọ Lacoste
O wa l'ara mi, o kùn sẹ, o tun ṣẹ danu
Fun ẹyin tẹ ko mi jẹ, tẹ n gbọn mi mu, ẹ ni ri idaamu

Kuronbẹ, ọmọ trenches ninu Lamborghini
VVS lọrun, j'aye Santorini
Aṣọ Gucci, ṣokoto Amiri
Ta ba ṣẹlẹ, wa mọ pe ẹṣa ni Richard Millie

Yeah, ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo
Uh, ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo
Ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo
Uh, ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo

Kuronbẹ, sẹ
Stack the money up, stack the money up, owo lo ṣe igboro (ki lo wi?)
Ra'le fun mummy, ra fun daddy, ma jẹ k'owo ṣe ojoro (ki lo sọ?)
Tẹ'pa mo'ṣẹ, ẹni ma ga, o di dandan, ẹsẹ a gun (jẹ ọ mọ)
O ma ṣiṣẹ, o ma laagun (jẹ ọ mọ)
O dẹ le sọ aagun dii igbadun

E no matter how the background dey be (ehn?)
O le di Arabanbi (ehn?) O dẹ sọ "bye-bye" si garri (si garri)
All man for himself, oju laarí
B'ọrọ yi ṣe n ba ẹ wi, bẹẹ naa lo n ba mi wi (ki lo sọ?)

Ọmọ trenches ninu Lamborghini (Lambo')
VVS lọrun, j'aye Santorini (gbe fun wo)
Aṣọ Gucci, ṣokoto Amiri
To ba ṣẹlẹ, wa mọ pe ẹṣa ni Richard Millie
Ẹṣa

Yeah, ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo
Uh, ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo
Ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo
Uh, ọmọ ologo, to ba ti ri mi, o r'ọmọ ologo

Kuronbẹ, sẹ
Stack the money up, stack the money up, owo lo ṣe igboro (o wọnu ogo)
Ra'le fun mummy, ra fun daddy, ma jẹ k'owo ṣe ojoro (well, well)
Tẹ'pa mo'ṣẹ, ẹni ma ga, o di dandan, ẹsẹ a gun
O ma ṣiṣẹ, o ma laagun
O dẹ le sọ aagun dii igbadun

So



Credits
Writer(s): Temidayo Rapheal Omoniyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link