Adura

Imole
Ayan, ayan, ayan
Aya ya ya ya ya aya
Mohbad
Shmurda ye

Baba gbo, gbo adura mi o
Baba gbo, baba gbo adura mi o
Baba jhor, baba jhor wa ṣẹ tẹmi ọ
Baba jhor, baba jhor wa ṣẹ tẹmi ọ

Ọ ba dakun gbọr, gbọr adura mi
Baba gbọr, baba gbọr adura mi
Ọ dun tun tun ti de tan
2020 tunti sunmọ
Baba gbọ gbọ adura mi o
Gba dura mi gọkẹ lhọr
Ka yẹ ma ṣẹ rimi mu
Gba dura mi gọke lhọr, kọ bimi ma ṣẹ sunkun
Na wetin i wan chop i dey find kin ma ṣẹ kpade nkan to ma jẹmi ọ

Baba gbọ gbọ adura mi ọ
Holy michael, holy yurel
Tọba gbẹmu oluwa fire them
Holy michael, holy yurel
Tọba gbẹmu oluwa fall their hand
Oluwa fall thier hand
As i dey smile they wanna see me frown

Ọ ba dakun gbọr, gbọr adura mi ọ
Baba gbọr, gbọr adura mi ọ
Ọ dun tun tun ti de tan
2020 tunti sunmọ
Baa gbọ gbọ adura mi ọ

Ki December má má di wa meru
I want to see January
Shọ mọ pẹ mi ọ ni ẹbi mi ọ lara ọluwa lọn sọr mi
Awọn tọn wa ọmọ oluwa wipe there tears
Awọn padi mi tọn ṣaṣẹ ki ẹnu wan ma se gbẹ
Imọlẹ

Ajẹ on d mix



Credits
Writer(s): Akinbiyi Ahmed, Oladimeji Ilerioluwa
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link