Layo, Layo

Láyọ' láyọ', la ju'ba' Rẹ
Olo'go at' Onífẹ'
Ọka'n wa ṣi' bi' ododo
Ti n' ṣí si' o'o'ru'n lo'ke'
Yọ 'kuku' ẹ'ṣẹ' o'n 'ba'nújẹ'
Móo'ku'n 'ye'méji' kúro'
Olu'fu'nni láyọ' a'i'kú
Fi'mọ'lẹ' ọjọ' kúnnú wa.

Iṣẹ' Rẹ fayọ' yí Ọ ka
Ay' ọ'run ta'n 'ta'nṣa'n Rẹ
'Ra'wọ', áńgẹ'l' ń kọrin sí Ọ
A'árín gbu'ngbu'n 'yi'n pipe
Pápá, igbó, pẹ'tẹ'lẹ', o'ke',
A'ku'rọ', o'kun didan
Ohu'n ẹyẹ, orísun t'ó ń ṣa'n
Pe' wá latí yọ' n'nú Rẹ

O' ń fifún ni, O' ń dáríji'
Ol'bu'ku'n, Alábu'kún
'Wọ l' orísun ayọ' i'ye'
I'jìnlẹ' i'simi
'Wọ Baba wa, Krist' Ẹ'gbọ'n wa
Tirẹ la'wọn tó nífẹ'ẹ'
Kọ' wá ba ti ń fẹ' ara wa
Gbé wa sáyọ' a'to'ke'wá

Ẹ'dá gbogbo gberin ayọ'
Táwọn 'ra'w' o'órọ' bẹ'rẹ'
Baba 'fẹ' ń jọba lori wa
Ẹ'gbọ'n 'fẹ' so wá papọ'
Lo'rin títí, a ń tẹ' síwájú
Aṣẹ'gun láa'rin i'ja'
Orin ayọ' gbé wa sóke'
N'nú orin 'ṣẹ'gun iye



Credits
Writer(s): Ayobami Kehinde
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link