Alhamdulilah (feat. Barry jhay)

LIB (Young Pee, sound it, please)

Èmi ni Barry Jhay o
Kosèyán níbè, Ọlọrun lowa níbè, eeehi

LGB (tèmi bawa ìrètí ṣimbe)
(Ti mountain o ba tan l'Ado Èkìtì ṣimbe)

When I wake in the morning, alhamdulilah, hmm, alhamdulilah
Má dé b'Ọlọrun mí sọrọ, koma yamutu mi bayìí o
Hmm, kode ma yamutu mi bayìí o
When I wake in the morning, alhamdulilah, o eh, alhamdulilah
Má dé b'Ọlọrun mí sọrọ, koma yamutu mi bayìí o
Hmm, ko ma yamutu mi bayi

Hmm, alhamdulilah, ahan
Alhamdulilah, ahan
To baji, alhamdulilah, ahan
Hmm, alhamdullilah, ahan
Hmm, alhamdulilah, ahan
Eh, alhamdulilah, ahan
Ahn, alhamdulilah, ahan (LGB)
Hmm, alhamdulilah, ahan

Wo, me, I still dey try ki Ọlọrun de hustle mí Ladé (Ọlọhun)
Mofe ni impact bi Mósè Orímolade (Ọlọhun)
Mofe fresh bi Adekunle Gold, ẹyán Baba Imade
Ki ńma wine, ki ńma dine pẹlu Ọba Aládé
Ọlọrun, jọ, ṣàánú fún mi, ṣiju anu wo mí (mhm)
Wọn tifẹ fema pé mi ní smellow nínú àdúgbò mí (ehn?)
Garri mí pẹ'lú epa, otipẹ tí mo tí ń soak e

Moni mofe gbemu nsin, ẹyin lẹyin fe take e
Wo, wo, kole possible o (never)
O da pe ẹfẹku (kobaa)
Mí ole bere' kilo fẹ 'cause mio ńṣe AB Cool o
Mi onshomo olówó, o pemi l'omo tálákà
Ìyẹn o mean pé mí o ní padà ra ilé sì Canada
I hustle hard bi ọmọ tí o lebi
Tẹ barimi timo gbé 'bọn, ẹma dàmi lebi
Wo, moti pá ọkan mí po sọ'dọ' Ya Robi
Faith mí o shake even timba wọnú galloping (ghrrr!)

Oooh, blessings every day, say blessing is all I see
Every single day you dey shower your blessings on me
Thanks for the blessings, thanks for everything
Thank you, thank you, thank you, oh Daddy
'Cause o ṣe, o ṣe, o rẹ ilé aláwò
Wọn ṣe, wọn ṣe, wọn rẹ ilé oníṣègùn (o ṣe)
Ko s'èyàn níbè, Ọlọrun lowa níbẹ', eeeehi

Ìwọ lonii kemi má bẹrú, pé ki ńmá fòyà
Pe ki ńmá lọ, ṣebí Jah Jehova ní o
Òun ṣá lo ń ṣọmi o, òun lalatilẹhìnmí
Òun ṣá lo ń ṣọmi
Ṣebi Jah Jehova ni o, òun ṣá lo ń ṣọmi o, òun ṣ'alatilẹhìnmi
Òun ṣá lo ń ṣọmi, oooooo eh

When I wake in the morning, alhamdullilah, hmm, alhamdullilah
Ma de b'Ọlọrun mí sọrọ, koma yamutu mi bayìí o
Hmm, kode ma yamutu mi bayìí
When I wake in the morning, alhamdullilah (ah-ah), eh, alhamdullilah
Ma de b'Ọlọrun mí sọrọ, koma yamutu mi bayìí o

Hmm, ko ma yamutu mi bayìí
Hmm, alhamdulilah, ahan
Alhamdulilah, ahan
To baji alhamdulilah, ahan
Hmm, alhamdulilah, ahan
Hmm, alhamdulilah, ahan
Eh, alhamdullilah, ahan
Ahn, alhamdulilah, ahan
Hmm, alhamdullilah, ahan

Ìwọ lónìí kemi ma bẹrù (emi ní Barry Jhay o)
Pẹkin ma fòyà (LIB) pẹkin ma loor
So, when I wake in the morning, alhamdulilahi, ahn (LGB)
(Young Pee, sound it, please)



Credits
Writer(s): Oluwakayode Junior Balogun, Tolulope Idris Taiwo
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link