Ore Ofe

Kii se nipa agbara wa
Kii se nipa ogbon ati oye
Bikose nipa ore ofe
Ore ofe sha
Kii se nipa ise apa wa
Kii se nipa igbala wa
Bikose nipa ore ofe
Ore ofe sha
Ore ofe la ntoro
Lati ba wa gbe titi
Kase irorun wa lori wa
Ore ofe sha

Oro re wipe Noah ri ojurere
Laarin awon eniyan to wa nigba re
Nipa ore ofe lofi ri ojurere
Ni ko fi bawon segbe
Esteri nikan ko ni wundia laafin
Kii se pe ohun naa to daa ju laafin
Sugbon ore ofe lori esteri
Ni a fi yan ni olori

Kii se nipa ogbon ati oye
Bikose nipa ore ofe
Ore ofe sha
Kii se nipa ise apa wa
Kii se nipa igbala wa
Bikose nipa ore ofe
Ore ofe sha
Ore ofe la ntoro
Lati ba wa gbe titi
Kase irorun wa lori wa
Ore ofe sha

Oro re wipe mo ri labe orun
Wipe ere ije kii se teni to yara ju
Ogun kii se teni to lagbara ju
Ore ofe ni
Ounje kii se ti ologbon
Oro kii se teni ti o loye
Oju oro kii se teni to logbon inu
Ore ofe ni

Kii se nipa ogbon ati oye
Bikose nipa ore ofe
Ore ofe sha
Kii se nipa ise apa wa
Kii se nipa igbala wa
Bikose nipa ore ofe
Ore ofe sha
Ore ofe la ntoro
Lati ba wa gbe titi
Kase irorun wa lori wa
Ore ofe sha

Ore ofe lohun
Adun ni leti wa
Gbohun re yi o gba orun kan
Aye yi o gbo pelu
Ore ofe sha
Nigbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
Je ki ore ofe yi
Fi agbara fun okan mi
Kin le fi gbogbo ipa mi
Ati ojo mi fun o
Ore ofe sha
Nigbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
Ore ofe sha
Nigbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu

Ore ofe la ntoro
Lati ba wa gbe titi
Kase irorun wa lori wa
Ore ofe sha
Ore ofe la ntoro
Lati ba wa gbe titi
Kase irorun wa lori wa
Ore ofe sha
Ore ofe la ntoro
Lati ba wa gbe titi
Kase irorun wa lori wa
Ore ofe sha



Credits
Writer(s): Awoyomi Oluwabukunmi Abraham
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link