Oppression

Monday to Sunday
2-47 mo fi ń teke mọ́jú
Bọbọ o ki ń sún
Body IP, a tun wẹ ọṣẹ mọ́jú
Too many format
Mo ṣe lotto, mo tun ló ṣe dating
Bọbọ, ko easy, oṣù mẹ́fà la ma ń fi gba 50

My mama call me
O ni, "Rano, ọmọ mi, I swear, you are dulling"
Ko tètè ye mi
A figba ti mo ri padi mi to ń gun Bentley

Oppression l'ọtún, l'ọsí
Kò ṣeni to like oloṣí
Ẹlẹda mí, dakun, masun
Ẹlẹda mí, dakun, masun
Oppression l'ọtún, l'ọsí (oppression l'ọtún, l'ọsí)
Kò ṣeni to like oloṣí (kò ṣeni to like oloṣí)
Ẹlẹda mí, dakun, masun (ẹlẹda mí, dakun, masun)
Ẹlẹda mí, dakun, masun (ẹlẹda mí, dakun, masun)

Pe k'ọ to gbowo yẹn, ojú ti ri gan (ri gan)
For Èkó Ilé, oju mi ri nkan (ri nkan)
Everybody hustle kikan-kikan (kikan)
Be like everybody gan lara ń kan
Pe k'ọ wọn to gbowo yẹn, ojú ti ri gan (ri gan)
For Èkó Ilé, oju mi ri nkan (ri nkan)
Everybody hustle kikan-kikan (kikan)
Be like everybody gan lara ń kan

Ogun ti gbe ibọn
When you see me, no dey form King Kong
When I kill show I use big gun
And the money go long like python
Ogun ti gbe ibọn (gbe bọn)
When you see me, no dey form King Kong (King Kong)
When I kill show I use big gun (big gun)
And the money go long like python

Oppression l'ọtún, l'ọsí (oppression l'ọtún, l'ọsí)
Kò ṣeni to like oloṣí (kò ṣeni to like oloṣí)
Ẹlẹda mí, dakun, masun (ẹlẹda mí, dakun, masun)
Ẹlẹda mí, dakun, masun (ẹlẹda mí, dakun, masun)

Oppression l'ọtún, l'ọsí (oppression l'ọtún, l'ọsí)
Kò ṣeni to like oloṣí (kò ṣeni to like oloṣí)
Ẹlẹda mí, dakun, masun (ẹlẹda mí, dakun, masun)
Ẹlẹda mí, dakun, masun (ẹlẹda mí, dakun, masun)

Monday to Sunday
2-47 mo fi ń teke mọ́jú
Bọbọ o ki ń sún
Body IP, a tun wẹ ọṣẹ mọ́jú
Too many format
Mo ṣe lotto, mo tun ló ṣe dating
Bọbọ, ko easy, oṣù mẹ́fà la ma ń fi gba 50

O-oṣù mẹ́fà la ma ń fi gba 50
(Ẹlẹda mí, dakun, masun)

Credits
Writer(s): Rano Whale
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link