Fuji Interlude

Mo kí rá fun Ọba Ilayi
Tí o dójú tí mí o
Ko sí ẹní t'omọ là t'oko
Ẹ'mí náà àá d'eyán o
Ẹlẹ'dàá mí má jẹ rá m'àyé
Ehhh, mo tí dé bí mo ṣe ńdé o
Mo tún-tún gbé èrè mí dé o
Oluwaloseyi o
Ẹní fẹ ná mí owó o kó wa bí

Bisi-Bisi, ní wo yí? (ní wo yí?)
Sexy Mama, ní mà yí (ní mà yí)
Ṣé o má lo mọ singer yí (singer yí)
Everyday ká ní bà yí (ní bà yí)

Àwọn kàn tí kó ṣí wàju, wọn tún kó'rin ni sí yín o
Àwọn kàn wá pọ níwájú, Alabi o wesẹ mí o
Bá mí kí Bàbá Balo
Ẹní jẹun lo má yo

Ìkú má pá brother mí o
Kí ikú má pá maga mí o
K'emí r'owó ṣayé
Wọn gbọ mí ní Germany dé'Ibafo
Kó mọ gbà t'owó kú wazo o
Àwọn girl tí wo Palazzo

Óyà, baby mí, wá jo
O tí mọ p'owó dé kún'lé o
50 Million ẹ-ku wazo
Money dey tí má ká o
Seyi, Malaika
Àwọn kán fẹ gará ní massion o

When I say óyá-óyà, let's dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lo s'agbo Loseyi oo

Óyá-óyà, let's dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lọ s'agbo Loseyi oo

Óyá-óyà, let's dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lọ s'agbo Loseyi oo

Óyá-óyà, let's dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lọ s'agbo Loseyi oo

Woo!



Credits
Writer(s): Afolabi Oluwaloseyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link