Sunshine
(Ob')
(Obah)
(Ọlọladé mí, Àṣakẹ)
Ọmọ ico, calcu' (calcu', calcu'-)
Ó fẹ l'owó bí Dangote, ò ní láti ja'gun
Ìgbádùn ayé pọ lẹyin ìpọ́njú
Mábẹ̀rù, rọjù
Sun's gon' shine on everything you do
Ọmọ ní òun ó lé wakú (wakú)
Abu tí gbé banku (banku, banku, banku)
No dey form say you jaju, try to dey calcu' (calcu')
Highly Celestial handles my situation
All my pains and my troubles
Steady lighting my candles
Chop knuckle, if you're part of the struggle, no wam
Sun's gon' shine on everything you do
Ahn-ahn-ahn, ahn-ahn-ahn, ahn
Ahn-ahn-ahn, ahn-ahn-ahn
Sun's gon' shine on everything you do (rock)
Kí ló ńbọ' lókè, ti'lẹ' o gbà (ti'lẹ' ó gbà)
Happiness on the way, oh my God
Light up my fire, l'olókè
Mr. Money, èmi ọmọ olóore
Ṣége, wọn má rí ṣége, ṣége
E don tey wey I don see Dende
I be the real vibe, me no be Yaya Toure
Da'wo sókè, Dami Damoshe
Eyes on, me, I no be bọlọ (bọlọ)
Jamo' l'ọmọ mí, no be sọdọ (sọdọ)
Mo ní irú ẹ ń 'lé, jẹ ká s'ọrọ (s'ọrọ)
Ìbádí ní pọnmọ, gbé sún mọ mí, jọwọ
24 carat, Saati, baby, já sí
I be classic, Illmatic, bad boy from starting
Ọmọ ìyá mí, ilefo Illuminati
Ọmọ ico, calcu' (calcu', calcu', calcu')
Ó fẹ l'owó bí Dangote, ò ní láti ja'gun (ja'gun, ja'gun, ja'gun)
Ìgbádùn ayé pọ lẹyin ìpọ́njú (ìpọ́njú, ìpọ́njú, ìpọ́njú)
Mábẹ̀rù, rọjú (rọjú-)
Sun's gon' shine on everything you do
Ọmọ ní òun ó lé wakú (wakú)
Abu' tí gbé banku (banku, banku, banku)

Ahn-ahn-ahn, ahn-ahn-ahn, ahn (iyo-oh, oh-oh)
Ahn-ahn-ahn (iyo-oh, oh-oh), ahn-ahn-ahn
Sun's gon' shine on everything you do (rock)
Ahn-ahn-ahn, ahn-ahn-ahn, ahn (iyo-oh, oh-oh)
Ahn-ahn-ahn (iyo-oh, oh-), ahn-ahn-ahn

Credits
Writer(s): Unknown Composer Author, Olamide Adedeji, Marcel Akunwata, Ololade Ahmed
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.