Adura

Ape manra la npe temi Dire wi tele mi bayii
Odun tuntun lawayii
Kire wamiri
Ko nonmi koshi, konon mashe di
Odun tuntun lawayi ohh
Kire wamiri
Kononmi koshi, konon mashe di
Ki nri batishe ehh
Ki nrona gbegba ahh
Ki nlowo lowo (ashe)
Ki nkole mole
Sope ki nri batishe ehh
Ki nrona gbegba ahh
Ki nlowo lowo (aminnn)
Ki nkole mole (oyaa)
Adara funmii
Adun fumii
Won ni wamitii
Won ni gbemisin

Adura lo ngbaa agbara koo
Adura nioo, agbara koo
Adura lo ngbaa, agbara koo
Adura nioo, agbara koo

Gba adura mi goke loo
Oke towo osho ko le deoo
Inu mi adun, ayo mi akun
Mio ni sukun, dun mi ninu
Inu mi adun, ayo mi akun oo
Mio ni sukun, dun mi ninu
Shonan mi nire, shiju anu womi
Shanu funmi, kota man yomii (Amin)
Adura lo ngbaa agbara koo
Adura nioo agbara koo
Adura lo ngbaa agbara koo
Adura nioo agbara koo
Opo lajo shodun to koja
To je pe won o siman
Ao fi yowan a fin ndupe ti wani
Opo lo nbe l'hospital ti won nwa iwosan
Baba mimon ope mi re ooh
Emi lolope baba wa gbo pemi
Omo olope ree moshe mope wa
Emi lolope wa gbo pemi baba
Olope ree motie mope wa ohh
Emi lolope koredee loverboy
Shebi graçüs loshe hit yioo
Koleyewon ohh
Odun yii odun mi nioo



Credits
Writer(s): Korede
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link