Allow Me

(Beats)

Ẹ jẹ kí ń sa fún ayé o, allow me
Ìgbà t'ọwọ ayé ba Sala, Salami
Èmi ọmọ Jésù ati Anọbi
Allow me to pull up in Ferrari
Allow me to gbà Richard mille kàn
Ki ń tún gbà Lamborghini kàn
I no need to ṣàlàyé anymore
Ọmọ oro tí upgrade, o tí lọ

Ikú ma pá mi o, asarailu
Mo tí ke pé jala jalailu
Mo tí fí Quran gbà àdúrà pẹlu Bible
Olùwà mi, I'm your loyal disciple

I dedicate my life to this course
Ọmọ oro mi, nothing to discuss
Ẹbẹ ni mo bẹ, Bàbá, jẹ k'àyé mi nítumọ̀
Jọ, ma jẹ ki ń r'ògùn brain tumor
Ṣé bí Olùwà lo mọlà
Ṣébí tita riro la fí ń kọ"lá
Ẹ jẹ kí underrating mọ ní ìwọ̀nba
'Cause this life no balance

Pẹlu ọrọ subsidy, full tank ni t'ọla ni
Èpò tan 'nu motor, f'ọla, f'ọlarin
Ìjọba wọn o sàn salary
Ejò r'owó e, loba gbé mi sharpally

Ẹ jẹ kí ń sa fún ayé o, allow me
Ìgbà t'ọwọ ayé ba Sala, Salami
Èmi ọmọ Jésù ati Anọbi
Allow me to pull up in Ferrari
Allow me to gbà Richard mille kàn (beats)
Ki ń tún gbà Lamborghini kàn
I no need to ṣàlàyé anymore
Ọmọ oro tí upgrade, o tí lọ

Ki'kú ma pá mi o, asarailu
Mo tí ke pé jala jalailu
Mo tí fí Quran gbà àdúrà pẹlu Bible
Olùwà mi, I'm your loyal disciple

I dedicate my life to this course
Ọmọ oro mi, nothing to discuss
Ẹbẹ ni mo bẹ, Bàbá, jẹ k'àyé mi nítumọ̀
Jọ, ma jẹ ki ń r'ògùn brain tumor

Ẹ jẹ kọ má sọrọ mí-
Kọ má sọrọ mi lọ
Steady counting my million
Counting my million

Eazy, wizzy, wizzy, wi-, sabi am
Eh-hey, eh-hey
(Aje on the mix)



Credits
Writer(s): Oladotun Olatunji
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link