Ki i Koni

Ẹbi lẹ kọ ni
Ki Ara kọ ni
Ki ẹgbọn kọ ni
Ki aburọ salọr
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọ
Ti kin kọni ọọ
Ẹbi lẹ kọ ni
Ki Ara kọ ni
Ki ẹgbọn kọ ni
Ki aburọ tun salọr
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọ
Ti kin kọni ọọ

Ọ kin kọni ọọ koni
Ọ kin kọni ọọ kin kọ' ẹyan
Ọ kin kọni ọọ koni
Ọ kin kọni ọọ

(Thank you lord Jesus)

Tọ ba jẹwi pẹ ọ kọ wa ni asiri wa ọ ti tu
Gbọ gbọ nkan ti an bọ titi ni ọ wa

Ọwun gan mọ kpẹ packaging lan fi si
Sungbọn packaging ti wa kọr lọ jekọ fine
Packaging ti ti ẹ lọ jekọ make sense
Tọ ba ẹ lẹ si packaging yẹn
Ha
Ọkẹtẹ dẹ gba alatẹ kawọ lẹ ọri ni yẹn
Ọlọrun ti kin kọr ẹyan ọọ
Baba lẹ kọni
Ki iya kọni
Ki egbọn kọni
Ki aburo salọr
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ
Ti ki'n kọ ni ọọ

Ọ kin kọni ọọ kọni ọọ
Ọ kin kọni ọọ Jesu yin kọni ọọ
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ ọọ ti kin kọ ni ọọ
Kọni ọọ koni ọ
Kọni ọọ koni ọ
Kọni ọọ koni ọ
Ti kin koni ọ ọọ
Ọ kin kọni ọọ koni
Ọ kin kọni ọọ kin kọ' ẹyan
Ọ kin kọni ọọ koni
Ọ kin kọni ọọ

Tọ ba je ti ayẹ tin gbani tọtin gbani sẹgbẹ
Ti wan kọ ẹyan ni, lọ ma sẹn kọr ẹyan ni ẹni ẹko ti kpo ni ilẹ gan
Ọ kin kọr ẹyan ni
Ọ kin kọr ẹyan ni
Ọ jẹ kọr awọn ti ẹ
Ọni majẹmu ayọ ti kin dalẹ maju
A gbẹ ọ ga lọni, a sẹ ọ' lọba
Kin sẹ wipẹ ato dẹ ade fun ọ
Sungbọn afi ọpẹ wa dẹ ọ' ladẹ
Kọ kin sẹpẹ ato fi iru gẹrẹ lẹ ọ' lòwò
Sugbọn afi ọpẹ wa fi iru gẹrẹ lẹ ọ' lọ'wọ
Kin sẹpẹ a tọbe ka ni ah sẹsẹ fẹ fi ọ' jọ'ba
A kan fi ọpẹ wa sẹ awọn nkan wan yi

I will never be ungrateful to you o lord
I will never be ungrateful
I will never forget all that you have done
I will never be ungrateful

Tori baba ti kọ eyan lọju mi
Ti iya kọ eyan ọ
Egbon kọ ẹyan
Aburọ kpọṣẹ si
Iwọ ni kan lọ ku fun ọni tọwun yẹn ni ọ kọr ọ
Ẹ mi leni à bà tà ka fọwọ ẹ ra bẹbẹ
Ki ọru ẹ to pa ẹni
Ọ da ọru mumi kurọ lẹ gbẹ mi lọ'n jẹbẹ
Si bẹ
Jẹsu,ọ kin kọni ọọ
Ọ ọọ ọọ
Kọni ọọ koni ọ
Kọni ọọ kin kọni ọ
Kọni ọọ koni
Kọni ọọ
Kọni ọọ koni ọ
Kin kọni ọọ kin kọni ọ
Ọ kin kọni ọọ koni
Ọ kin kọni ọọ
Aye lọni kọ wọ ọọ
Iwọ lọni kọ wọ
Ayẹ lọni kọ fọr ọ
Iwọ lọni kọ fọr
Ayẹ lọni kọ la
Iwọ ni kọ la
Ọ un ti ọ ba gba ọ gba nọni yẹn
Ayẹ lọni k ọ fọr ọ
Iwọ lọni k ọ fọr
Ayẹ lọni k ọ bọ
Iwọ ni kọ bọ
Ayẹ lọni kọ tan
Iwọ lọni kọni tan
Ọ kin kọ ẹyan ọ

Kọni ọọ ọ je koni ọ
Kọni ọọ kin kọ ẹyan ọ
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ ti kin kọ ni ọọ
Kọni ọọ koni ọ
Kọni ọọ kọni ọ
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ ti kin kọ ni ọọ
Baba lẹ kọni
Ki iya kọni
Ki ebi kọni
Ki ore de salọr
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ
Ti ki'n kọ ni ọọ
Kọni ọọ ọ je koni ọ
Kọni ọọ kin kọ ẹyan ọ
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ ti kin kọ ni ọọ
Kọni ọọ koni ọ
Kọni ọọ kọni ọ
Iwọ ni kan lẹmi mọ ọọ ti kin kọ ni ọọ

Ọwọ ẹpo ni mọmọ ti ara yẹ bani la
Ọni bẹ lọwọ kọ ti tọri ẹ ba ẹ la ọwọ ẹjẹ yẹn
Iwọ ni kan lọ fẹ jẹ rami ọ, ọ kin kọni ọ

Kọni ọ ọje kọni ọ
Afi ẹni to ba fẹ ya lẹyin ẹ ni kan lọ ku
Iwọ nikan lẹmi mọ ti kin kọni



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link