Oluwa Ari'se Yin (feat. BBO) [Remix]

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Olúwa a ma ń rọwọ yín oo
Olúwa a ma ń ríṣẹ yìn oo
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

O máa ma ṣé elédùmarè
O máa ma ṣé o alátìlẹyìn
Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí
O máa ma ṣé o elédùmarè
O máa dúpẹ' dúpẹ' dúpẹ' alátìlẹyìn
Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù
Tó dúró tì mí lẹ'yìn
Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí
Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù
Tó dúró tì mí lẹ'yìn
Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí

Eeee eeee eeeeeee

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

Gbogbo àwọn tátí rán lọ'wọ' tán ṣe bí Ọlọ'run kò wá tán bí
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Gbogbo àwọn tọ' ti rò wá pín tán ṣe bi Ọlọ'run kò wá tán bí
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Eẹẹẹẹẹ
Ibi ẹ fojú sí ọ'nà o gbà bẹ
Mọ tí lọ mọ' yín lọ'wọ' oooo
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

Ẹhn ẹhn ẹhnẹhn

Translate to English

Credits
Writer(s): Bada Damilola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link