IRE & IBI

Kosoju to ma rire ti o ni ribi
Yoruba ni kosoju to ma rire ti o ni ribi
Gbomi dada, woni kosoju to ma rire ti o ni ribi
Kinikan ni momon to dami loju
Koju to ma ribi ti o ni rire
Aimoye ibi ti mori ti mo kigbe
Aimoye ibi ti mo subu ti mo dide
Aimoye ija ti mo ja ti mo selese
Aimoye ibi ti mo baje ti mo tunse
Oju mi ti ri many things ninu aye
Wahala, idamu ati ebi ti bami gbele
Aimoye ogbo ti moda kinle begbe pe
Bisoro kan tin jade ni mefa nde
Ebi, ara, ore ko mi
Emi ni adugbo to pe nile
Baba to bi mi komi, ole mi ninu ile
Iranlowo mana ni moni ti mofi rile gbe
Mapami, mapami, ma semilese
Iya mi o lorin meji ju ma semilese
Ogbon npa ologbon, omugo npe laye
Mose bi omugo kinba lepe laye
Kosuju to maribi tio ni rire
Mapami mapami ma semilese
Kosuju to maribi tio ni rire
Mapami mapami ma semilese
Opo lokole, wom o ni moto
Opo lora oko, won o koja Eko
Opo ti ku, opo sinbo
Opo lowa laye won o mojo tan lo
Owo wa, kosomo
Omo wa, won o rowo to
Owo wa, omo wa, ko soko
Oko wa, omo wa, ko sayo
Kosuju to maribi tio ni rire
Mapami mapami ma semilese
Kosuju to maribi tio ni rire
Mapami mapami ma semilese
Tan ba ni talon sere
Eso fun won pe The Barbers
Oga olorin lawa o maje
Oga onirun lawa o maje



Credits
Writer(s): The Rich Barber
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link