Ololufe (feat. Wande Coal) [Mixed]

Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)

Hmm, sọ fun wọn mo n'ifẹ
Mo ni, "Fọlashade"
Sọ fun ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni o

Layẹmi, Olayẹmi, mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Titilọla, hmm, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Mo ni, "Fọlashade"
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni

Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ re

Ko, ko, ko, ko
Konkobilo, ko, ko, ko
O wá fẹ pàdé mí ní ìsàlẹ
Ò yẹ ká fún konkobilo
Ko, ko, ko, ko
O wa fẹ jẹ ko, ko, ko, ko
Moni ko pàdé mí ní ìsàlẹ
Ìyẹn gan lo n ṣe ko-ko

Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem...)



Credits
Writer(s): Simisola Bolatito Ogunleye
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link