Apalapiano

Ojó tó tí pé
Oná ti jìn
Ó ti rò wa lorùn gan bí èko
Eni à jùlo ò mò
Ara ló jú opón
Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe
Irú Òkéré lóun ní a májá lérú
Oun téo leesé lén rawólé pápin
Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin
Erú olóko àwa nì won jé
Mo sèbà fáwon ti De' Vil
Selfpaid Records, OG Waliyi
Mr Tosin, sájé' n wogbá
Ofé ya photo
Pe baba Jayden
Bravolee tún ti sanwó mi
Èyan Olómi tó 'n ta BTC
Egbémidébè kín kí Israel Money
Gbogbowá tii màn pé òhun ló ni Moní
E tannán sáwon balógun
Málo béé sí won
Kóo máa lo gbì
Àwon a pète pèrò
Káa fowon wan lélè
Tán tún yàká sí everybody
Àwáá náàni táa múgboro dùn
Kaniel Pèdè Ó mórí wa wú
Tàsà tèdè kalè sódò wa
Nitori

Ojó tó tí pé
Oná ti jìn
Ó ti rò wa lorùn gan bí èko
Eni à jùlo ò mò
Ara ló jú opón
Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe
Irú Òkéré lóun ní a májá lérú
Oun téo leesé lén rawólé pápin
Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin
Erú olóko àwa nì won jé

Ojó tó tí pé
Oná ti jìn
Ó ti rò wa lorùn gan bí èko
Eni à jùlo ò mò
Ara ló jú opón
Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe
Irú Òkéré lóun ní a májá lérú
Oun téo leesé lén rawólé pápin
Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin
Erú olóko àwa nì won jé

Ojó tó tí pé
Oná ti jìn
Ó ti rò wa lorùn gan bí èko
Eni à jùlo ò mò
Ara ló jú opón
Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe
Irú Òkéré lóun ní a májá lérú
Oun téo leesé lén rawólé pápin
Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin
Erú olóko àwa nì won jé
(Ona ti Jin)
(Bi eko)
(Ara loju opon)
(Mátan raa re)
(Rawole papin)
(Ninu ile orin)
(Eru oloko awa ni won je)

Ojó tó tí pé
Oná ti jìn
Ó ti rò wa lorùn gan bí èko
Eni à jùlo ò mò
Ara ló jú opón
Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe
Irú Òkéré lóun ní a májá lérú
Oun téo leesé lén rawólé pápin
Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin
Erú olóko àwa nì won jé



Credits
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link