Mura Sise
Ma wori olori
Ma wola olola
Ma wojo olojo
O ba tete tera mo tie o ojo nlo
Ise ise nitoju
Owo ise ni sela
Ise ise nitoju
Owo ise ni sela
Ka ma fowuro sere
E jeka sise loworo kayee tale koju
Mura sise owo re o ore mi
Tepa mose owo re o ore mi
Ikan kiitiju aamole
Eera kiitiju aayena o
Ikan kiitiju aamole
Eera kiitiju aayena o
Mase tiju ise re o ore mi
Ise ise nitoju
Owo ise nisela
Ise ise nitoju
Owo ise nisela
Ka ma fowuro sere
E jeka sise loworo kayee tale koju
Gbogbo obi pata
O ye kamaa tomo wa lati'gba ewe
Lati maa tepa mose o jare
Ka maa fiy'awon omo wa wipe
Sise omo mi sise omo mi
Sise omo mi sise omo mi
Ise ni gbeni depo ola mura sise
Ise ni gbeni depo ola tepa mose
Tori Akuko ko ole pose ise
Ale nle inu ole ndun
Tori Akuko ko ole pose ise
Ale nle inu ole ndun
Ojo odun k'ola o ole n sare
Sise nitori oru nbo
Sise 'nu tana o omo baba
Sise nitori oru nbo
Sise 'nu tana o omo baba
Sise nigba iri se o ara mi
Sise nigba oorun ran o ara mi
Sise nigba asale koi tii de o
Mase sole mase tojo ale kanju
Ise loogun ise ara mi
Mura sise o mase sole
Ise loogun ise ara mi
Mura sise o mase sole
Ma wola olola
Ma wojo olojo
O ba tete tera mo tie o ojo nlo
Ise ise nitoju
Owo ise ni sela
Ise ise nitoju
Owo ise ni sela
Ka ma fowuro sere
E jeka sise loworo kayee tale koju
Mura sise owo re o ore mi
Tepa mose owo re o ore mi
Ikan kiitiju aamole
Eera kiitiju aayena o
Ikan kiitiju aamole
Eera kiitiju aayena o
Mase tiju ise re o ore mi
Ise ise nitoju
Owo ise nisela
Ise ise nitoju
Owo ise nisela
Ka ma fowuro sere
E jeka sise loworo kayee tale koju
Gbogbo obi pata
O ye kamaa tomo wa lati'gba ewe
Lati maa tepa mose o jare
Ka maa fiy'awon omo wa wipe
Sise omo mi sise omo mi
Sise omo mi sise omo mi
Ise ni gbeni depo ola mura sise
Ise ni gbeni depo ola tepa mose
Tori Akuko ko ole pose ise
Ale nle inu ole ndun
Tori Akuko ko ole pose ise
Ale nle inu ole ndun
Ojo odun k'ola o ole n sare
Sise nitori oru nbo
Sise 'nu tana o omo baba
Sise nitori oru nbo
Sise 'nu tana o omo baba
Sise nigba iri se o ara mi
Sise nigba oorun ran o ara mi
Sise nigba asale koi tii de o
Mase sole mase tojo ale kanju
Ise loogun ise ara mi
Mura sise o mase sole
Ise loogun ise ara mi
Mura sise o mase sole
Credits
Writer(s): Michael Omoshilade
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.