E Gbeyewo
Oro maree kegbe yewo - oro mare o kegbe yewo
Oro maree kegbe yewo - oro mare o kegbe yewo
Iberu oluwa ni ipinlese ogbon
Idajo ododo nii gb'orile-ede leke
Iwa otito pelu ife ni nfunni nigboya
Ni nmule toro ni mawujo toro
Ni nso orile-ede dalagbara
Oro mare kegbe yewo, omo yoruba
Oro mare o kegbe yewo
Sebi ogbon ologbon ni kiije ka pagba ni were
Omode gbon, agba gbon, lafi da'le ife
Taba s'oko oro s'ologbon eniyan, ofurufu ni yoti gbamu, o daju
Oro mare kegbe yewo
Oro mare o kegbe yewo
Oro sunnukun, oju sunnukun lafi nwoo
Enito jinsi koto, o ye kawon yoku 'o fi kogbon
Sugbon aja toma sonu konii gbo fere olode
Olukuluku eniyan lo ndaba ola
A ndaba odun kan, a ndaba odun mewa, koda, ogun odun tabi jubee lo
Sugbon eniti ku maapa, koniigbo girigiri ese
Eni t'Olorun fee mu, oniye osi ni gbariwo
Oro mare o tewe tagba, omo oodua nile loko
Oro mare o kegbe yewo
Awon taape wa jeun, tan muni lowo dani nko
Agbara 'o loun 'o wole, se bonile nio niigba
Kaka ki kiniun sakapo f'ekun, kolode o fotooto rode
Eniti kiki e ko yoni, aikini re kolee pani lebi
Adiye yogun o pogun, won ladiye o pomo re
Won gbadiye ta, won fowo e ra pepeye
Pepeye yogbon o pogbon, won tunni pepeye o pomo re
Won fi binu gbe pepeye ta won fowo e reyele
Eyele yeyin meji pere, o tun fi pakan soso
Keyele to pakan soso oun, seni won tepepe fun
Eyele lowa pomo re tab'adiye, e so fun wa
Oro mare kegbe yewo, omo Yoruba
Oro mare o kegbe yewo
Egbinrin ote, baati pakan, nikan nru
Iduro kosi, ibere kosi, feni to gbodo mi
Bawo lomo Oba yose wa daru, tomo ijoye yoose wa diwofa
Seboko kiije tibaba at'omo koma laala
Eyin asaju wa at'eyin igbimo lobaloba
Nibo lade duro, nibo gan lan lo
Aimete aimero, lomo iya mefa fi n ku soko egbaafa
Tabafe jagun molu, anilati fimosokan
Kokoro ti njefo, ara efo lowa
Sugbon bi'ro baa lo logun odun, ojo kan lotito o ba
E bawa kilo fawon atori-owo-baluje
Karanti pe, ile labo simi oko
Oro mare kegbe yewo, omo kaaro-oojiire

Credits
Writer(s): Michael Omoshilade
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.