Giddem

(Yo-)
(Big Vibez)

If to say na me be you
If I see Naira Marley
Ma ya sare ṣe twale
I go ask baba for way
Because igi imu jina s'ori
Ọmọ ma ra ko to rin

Sanmọ o le wa lẹ
Ẹjẹ kan mọ pe sanmọ o le wa lẹ
Oju ra wọn lọ
O skingba kan ju kan lọ
A nọ gbe fun kan ju kan lọ
Mo lo n bẹ bi kan ju kan lọ

And it's all on God (and it's all on God)
That we are still on top
Anything they like make them talk
Oun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ (bhrrr!)
O ti ṣẹlẹ bayi
Oti di agbo awọn wèrè bayi

Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (hello)
O ti ṣẹlẹ bayi
Oti di agbo awọn wèrè bayi
Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (hello)

To ba funmi dollar, ma gba (ma gba)
To ba funmi naira, ma gba (ma gba)
Pounds ma gba (ma gba)
To ba funmi l'owo, ma gba (ma gba)
Giddem, giddem, gidden, giddem
Giddem, giddem, gidden, giddem
Giddem, giddem, gidden, giddem
Giddеm, giddem, gidden, giddem (bhrrr!)

Ayеbo, ayeba
Somebody call the popo
Baba ibeji, iba jojo
T'emi ba n kọ'rin, ki iwọ ma jo (bhrrr!)
Ayebo, ayeba
Somebody call the popo

Baba ibeji, iba jojo
T'emi ba n kọ'rin, ki iwọ ma jo
O le tẹ 'go mọlẹ, ma lọ t'agba mọlẹ
Igo ma n ya 'yan l'ẹsẹ
Agba ma surprise ẹ
Basically, agba ma n ya 'yan l'ẹnu

And it's all on God (and it's all on God)
That we are still on top
Anything they like make them talk
Oun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ (bhrrr!)
O ti ṣẹlẹ bayi
Oti di agbo awọn wèrè bayi

Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (hello)
O ti ṣẹlẹ bayi
Oti di agbo awọn wèrè bayi
Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi

To ba fun mi dollar, ma gba (ma gba)
To ba funmi naira, ma gba (ma gba)
Pounds ma gba (ma gba)
To ba funmi l'owo, ma gba (ma gba)
Giddem, giddem, gidden, giddem
Giddem, giddem, gidden, giddem
Giddem, giddem, gidden, giddem
Giddem, giddem, gidden, giddem (bhrrr!)

(Big Vibez)



Credits
Writer(s): Azeez Adeshina Fashola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link