Clear

(Lilu)
(Shoka lo ṣe beats)

Shoka lolu beat oh
Ika producer carry me trabaye o
Orin n bẹ niku mi, anjọnu olorin, Ọmọlalọmi Akerin o
Them call me Portable Baby oh
Turn up, shaku-shaku

Wọn sare lọ, unfollow wa o tori wọn ri jẹ lara wa mọ
Ko si yẹn mọ, ọmọ ologo ti gbera tan
Moya tete ya danu o, k'ọn to para pẹlu Jagamu o
K'ọn ma lọ ka mi mọ, mo ya tete sapa mọ o
Na mi get Zazu, are you mad on something o?
I'm a bigi man, ṣe mo jọ talaka o?
Ọmọlalọmi Akerin o, them call me Portable Baby o
Turn up, Shaku-shaku o, emi ni wèrè olorin o

If you no get money (clear)
Ko ya tete ya danu o (clear)
Olowo ni ṣ'ọrẹ olowo (clear)
Olowo la wọn ọrẹ mi (clear)
Isọkusọ mapa data (clear)
Ṣọ'ra fun awọn ripper (clear)
If you no get money, ko ya, ko ya danu o (clear)
Clear, clear, clear, clear, clear, clear
Clear

Emi Ika o, baba Ika o, eyan Ika o, wu wa Ika o
Ika o le wo oju ka o (clear)
Ika n bẹru ika o (clear)
Ika o le dẹmọ fun ika o (clear)
Ika ranju mọ ika o (clear)

Ọmọ oro mi, know person o (clear)
If you trust person o (clear)
You go learn lesson o (clear)
Ọmọ better, more blessing o, ma lọ dapọ mọ ero
Dapọ abi ko danu o
Ọrẹ star, star ni o, gbogbo nkan by lucky ni o

If you no get money (clear)
Ko ya tete ya danu o (clear)
Olowo ni ṣ'ọrẹ olowo (clear)
Olowo la wọn ọrẹ mi (clear)
Isọkusọ mapa data (clear)
Ṣọ'ra fun awọn ripper (clear)
If you no get money, ko ya, ko ya danu o (lilu)
Clear, clear, clear, clear, clear, clear
If you no get money, ko ya, ko ya danu o (clear)

Wọn sare lọ, unfollow wa o tori wọn ri jẹ lara wa mọ
Ko si yẹn mọ, ọmọ ologo ti gbera tan
Moya tete ya danu o, k'ọn to para pẹlu Jagamu o
K'ọn ma lọ ka mi mọ, mo ya tete sapa mọ o
Na me get Zazu, are you mad on something o?
I'm a bigi man, ṣe mo jọ talaka o?
Ọmọlalọmi Akerin o, them call me Portable Baby o
Turn up, Shaku-shaku o, emi ni wèrè olorin o (lilu)



Credits
Writer(s): Mudashiru Olajide, Habeeb Okikiola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link