Opin Aye

(Òpin aiye' o) òpin aiye', ibí aiye' ń re yí, òpin ní, ah-ah-ah
Ilè aiye' tí ṣú o (ilè aiye' ń ṣú)
Òjò má ń lọ ní ilẹ' yí, ènìyàn, ṣe réré (ṣe réré)
Òpin aiye' (òpin aiye')
Òpin aiye', (ìbi aiye' ń rẹ) ibì aiye' re yí òpin ní
Ilè aiye' tí ṣú o (ilè aiye' o ṣú o)
Òjò ma ń lọ ní ilè yí, ènìyàn, ṣe réré (òjò ń lọ, ìgbà ń lọ)
Òpin aiye'

Ẹni tolórí, ẹ wá gbòòrò mo ní o
Ẹlétí tí o kùn, e bá mí wá gbà yí gbó
Òwúrò aiye' ìyẹn má tí kọjá o
Ọ'sán aiye' ń dí ìrólé bọ, ojú òjò ń ṣú o
Kololoja má gbàgbé, àsìkò ń lo, ò ń ṣú o e (ò ń ṣú o)

Òpin aiye', ibí aiye' ń re yí, òpin ní (ibí aiye' ń kó rí sí, òpin ní)
Ilè aiye' tí ṣú o (agba orí, eh-eh)
Òjò má ń lọ ní ilẹ' yí, ènìyàn, ṣe réré
Òpin aiye'

Mó wo íréré aiye' o, ayé ré bí àná bó o
Òkùnkùn ń subo, kol'oja má safira
Àsìkò tani lókè ẹepe, o fèrè pé o
Ke ní pàtẹ́ ọjà, Màtá kàkà, ò ní ṣú ọ
Olojo ń ka jo, ẹ'dá ọ fí ye sí, o de tàn o e (o de tàn o)

Òpin aiye', ibí aiye' ń re yí, òpin ní (ol'oja mama safira)
Ilè aiye' tí ṣú o (Ilè ṣú o)
Òjò má ń lọ ní ilẹ' yí, ènìyàn, ṣe réré (ol'ojo ń ka jo)
Òpin aiye'

Wá gbà Jésù lónìí, ọrẹ, má fí d'ọ'la
Ẹni tá wí fún, to lóhùn kogbà, yí o fí ìka bo'nù
Kos'ọnà míràn tọ le gbé wá délé
Tá ba j'adùn, ba ń jé ìkorò, ará, ẹ je a rántí o
Ikú ní o gbẹ̀yìn gbogbo wá, dandan ní o e (dandan ní ikú o)

Ayé e gbo oo (ah-ah, ah-ah, egbo), kọ má s'ona mìíràn mọ o
Taa lè gbà ye ge láyé (bẹẹni mo wí ọ)
Ẹniti tin se ibi yara kuro (yàrá, sáré tete kúrò níbẹ̀, Jésù yìn o)
Òpin ayé

Àṣàmo lòun to ń sele, l'aiye fi ń pa
Irokeke ní wá léyìn àti Ògún abelé
Èdè ayédé, lọkó, làyà, ayé do lobìnrin po
Oun tọ k rí sókè, ni josi ko rí sílè, o dàbí idán
Ká tọ ṣejù peren, ilè a má ṣú o
Jésù o nipedé, kẹ'léṣe ko wé yín wọ o
Bo'ja ba títú, pate-pate lo má kú (bo'ja ba títúu)

Òpin ayé de tán (odi de tàn nìyẹn)
À fí kí igbon, s'alayi gbọ'n o (pate-pate lo mi a ku)
Wáá má sunkún, sunkún (wá má sunkún, sukun o)
Èyí wá padà nílè yí, ènìyà, se réré (olojo o má dé, o má dé tan)
Òpin ayé

Ọrẹ ẹ wá gbo, e wá mọ ìfé Jésù yí o
Òjò má ń lo nílè yi, ènìyàn (ojo ń lo), ṣe réré (ṣeré o), òpin ayé
Ẹní wá ayé tí o ní Jésù, ayé asán lọ wà
Ẹniti ń ṣe'bì, yàrá kúrò lọ'nà ẹsẹ ré o (ee wí fún o, ayé bansa ní ọ)
Òpin ayé

Torí bọ lówó, bo lèèyàn, to ní fọn, to lekana
Èyí wá padà nílè yí, è mama se réré (ìyẹn o je kókó, a fi kọ yìwàpadàa)
Òpin ayé
Kọ jókò, ko dára, kọ ṣe ri mo 'nìyàn, kọ jẹ kókó o

Òjò má ń lo nílè yi, ènìyàn, ṣe réré (Jésù lọ'nà òtítọ' àti 'yè), òpin ayé
Ìwà òwò ré lá o wọ, aténì tọ ní o
(Ẹniti ń se ibì, yára kúrò lọ'nà, ese re o) ta lo ní o, s'eṣù ní àbí Jésù?
Òpin ayé
À ṣẹ ìgbàgbó má ṣé
È wá gbo mí, òrò kàn yìn o
Èyí wá padà nílè yí, ẹ mama ṣe réré
Òpin ayé

À jẹ nílè ìjọsan bí ekute, ẹ kú ìfé o
Òjò má ń lo nílè yi, ènìyàn, ṣe réré
(ẹyin ojojùmọ̀ ilé ìjọsìn, egbo, ṣe ń ṣe dáadáa?) òpin ayé
È dijù, è gbàdúrà tí torí owó tẹ fẹ kọ
(Ẹniti ń se ibì, yára kúrò lọ'nà, ese re o) yara kuro kíákíá, kojo to de bá o-
Òpin ayé
Aríran òdì àti oní gbà ní nímọ̀ràn tó ń tú ilé ká
(Èyí wá padà nílè yí, ẹ mama ṣe réré) èé, Olúwa mí ń wo yìn, o fowó lè rán
Òpin ayé
Ojú Olúwa ń woyín, o fere dé, bí olè e

(Òjò má ń lo nílè yi, ènìyàn, ṣe réré) tọ bá dé, ìkòkò òní gbomi ko tún gbe
B'òkùnkùn báti ṣú, a d'oju olomo o to, ìbò le o gbá?
(Ẹniti ń se ibì, yára kúrò lọ'nà, ese re o) ahh, kúrò lọ'nà ẹsẹ re o
Òpin ayé
Ọrọ rẹ o, to bá kú le kun, má mù wabo 'jo
(Èyí wá padà nílè yí, ẹ mama ṣe réré) fún Olúwa ba rán mí, ma tunmúwá ehh
Òpin ayé
Fáyé rẹ fún olùgbàlà tọ lẹ dá o gbá (Jésù ní)

(Òjò má ń lo nílè yi, ènìyàn, ṣe réré) Jésù nikan lọ'nà tọ le gbe o délé oh
Òpin ayé
Sí ilẹ̀kùn ọkàn re sílè, má tí ilẹkun mo sìtá
(Ẹniti ń se ibì, yára kúrò lọ'nà, ese re o) okokun, okokun, ọrẹmí sí ilẹ̀kùn ọkàn rẹ o
Opin aiye

Ikú orí àgbélébùú mama jẹ ko ja sasan
(Èyí wá padà nílè yí, ẹ mama ṣe réré) ẹ mama je ko já sasán, owá sáyé torí eyín
Òpin ayé
Òpin ayé e dé tàn o, ẹ gboro mí, e mama pada
(Òjò má ń lo nílè yi, ènìyàn, ṣe réré, òpin àyè



Credits
Writer(s): Tope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link