Tanadi

Jerryson production
Tanadi arawa, koma ma da erora
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Tanadi arawa, koma ma da erora
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Naam
Oun tomaje ti teni, kole fonida laye
Teda ba nsebaje sibi tati ndogbon
Pe kebi ma pomo wa atiyawo wa ni
Benikan fe dina atije atatimu wa
K'olohun bawa febi atedi se tiwon
Kota o toro je kosi ni moribo
Tanadi arawa, koma ma da erora
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Nemesis loyinbo ma npesan toba de
Eni tonse rere loni kole gbe laye
Koda bonfibi su, yio gbesan toba ya
Eni aba seka fun, kokan miri lasan
Esan a ke dandan, nigba toba ke tan
Sereni to nsebi fun nlati jeka toba ya
Tanadi arawa, koma ma da erora
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Sababi arawa, eyi taba fe je
Kaje si ti rere laiseka funrawa
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Malaika tonko rere, otun londuro si
Eyi to nko tibi, egbe keji londuro
Sapamo kajori, ama wo e rekete
O koja pe moti ti ilekun mi ni kokoro
Tanadi arawa, koma ma da erora
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Ore o gbe e iro lopa, o lowokan ika ninu
Bareni tonse rere, ko ma legbe laye
O le ma jodo eni, to fokansi rarara
Ma foju sunbi ore, p'oma gbawa to ba ya
Yoruba ntenumo, oro kan won a wipe
Basore fun arara, omiran la gbewa
Tanadi arawa Koma ma da erora
Oun abase loni, bo dola a yiwa
Wa semi lakin, fidunnu tami lore
Maje nbekun sun, maje nbekun ji
Wa semi lakin, fidunnu tami lore
Maje nbekun sun, maje nbekun ji
Oba mafaye mi sile, kemi nikan o dagbe
Loni alo jeun, enikan lo mowo le
Ola alo raso, enikan raso funmi
Bonse nsore funmi, jekinle ma se funyan
Konma yomi legbe, wa tete tami lore
Ma je nte lebi, ma yomi lara
Wa semi lakin, fidunnu tami lore
Maje nbekun sun, maje nbekun ji
MashaAllah
Nigba ti ko sowo, moma wa lalafia
Towo bawa de, ma faisan demi mole
Maje kin foshi mo awon eyan tiwon femi
Kaye ma fiku mo iwa timoni toda
Kin se party rero, kin bale mo entokomije
Kin nfowo pelere, ko f'apo shaka k'owo lo
Wa semi lakin, fidunnu tami lore
Maje nbekun sun, maje nbekun ji
Eni to sun lale ana pelu sadness
O ji loko keji, koma masi happiness
Gba p'olohun loba tole sore express
Lo fokan bale. Ko lewa ni readiness
Pa ironu ti. Kole wa ni wellness
Tori tola bade, koba e pelu fitness
Wa semi lakin, fidunnu tami lore
Maje nbekun sun, maje nbekun ji
Bee!
Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o
Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o
Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o
Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o
Yaaa robbi
Olohun oma ku ise o, ni gbogbo igba monrise e
Nidi isemi mohan nbe o, aga niwaju lo tomi sio
Emi naa ko, isesi mi naa ko lodaju
Oore ofe nmori gba o
Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o
Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o
Allah
Okiki ayo nile wa, ariwo ayo nilemi
Aanu e timoma tinwa o, koje nrigba loni o
Womise laanu, adua mi oba je o gba, oloore ofe ni o, Allah
Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o
Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o
MashaAllah
Oba atobiju ma funmi lo, o kuku timo ma dupe o
Oore totun-tosi jenri gba o, oore tiwa teyin ko bami
Maje ko fomi, koma kojaa mi yah robbi
Oloore ofe ni o ooo
Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o
Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o
Morire gba mo kore, ire ayomi nlekun
Emi rire gba mokore, ire ayomi nlekun
Moni kin femi ro ni, loba gbabe ja sope
Inumidun mojelo, modupe koja s'asan
Ma beru maselo, aimoye danwo tonjawo
Opportunity ojo kan ma nsoni deyan laye
Morire gba mokore, ire ayomi nlekun
Emi rire gba mokore, ire ayomi nlekun



Credits
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link