Journey
Ẹjẹwọ, ẹ má pa mi
Gbogbo òṣì tí ẹ sọ yẹn kọ'mátà ni
Lo ṣe jẹ' kín face bukata mi
Tọmọde àti àgbà ló like pattern mi
Ó sure pé wọ'n má gbe wa
Ó sure pé mà ri rábà mi
Mo jáde tán mo buckle sanda mi
Ẹlédà kò gbà mí
Bad energy ké yà kò gbà yín, ké yà kò gbà yín
The journey far
Mò ń lọ ibi gíga
I be hustler, kí n má rí gbà
Mo kan rí pé mo jẹ' lọ́, ǎánú nì mo rí gbà
This music thing i too sabi
Mà fi ọmọ wé ọmọ, kò lè dàbí
Ṣọ'rẹ' ṣọ'rẹ' màmá rí gbà ní
À máa rí gbà ní
Wọn jámi, emi ní mo járami
Owó tí mo ní, ní mo ya ara mi
Several times tí mo ṣùkùn nínú yàrá mi
Look at me now ẹ'yin ara mi
Ọmọolórè wọn lè gba kádàrá mi
Ọmọolórè ò ní mofò
When there is no money kíní kókó
Ẹlẹ'nù pèlẹ'bẹ' olófofò
Pẹ'lú gbogbo tì ẹ sọ, kíní kókó
Kíní kókó
Gbogbo òṣì tí ẹ sọ yẹn kọ'mátà ni
Lo ṣe jẹ' kín face bukata mi
Tọmọde àti àgbà ló like pattern mi
Ó sure pé wọ'n má gbe wa
Ó sure pé mà ri rábà mi
Mo jáde tán mo buckle sanda mi
Ẹlédà kò gbà mí
Bad energy ké yà kò gbà yín, ké yà kò gbà yín
The journey far
Mò ń lọ ibi gíga
I be hustler, kí n má rí gbà
Mo kan rí pé mo jẹ' lọ́, ǎánú nì mo rí gbà
This music thing i too sabi
Mà fi ọmọ wé ọmọ, kò lè dàbí
Ṣọ'rẹ' ṣọ'rẹ' màmá rí gbà ní
À máa rí gbà ní
Wọn jámi, emi ní mo járami
Owó tí mo ní, ní mo ya ara mi
Several times tí mo ṣùkùn nínú yàrá mi
Look at me now ẹ'yin ara mi
Ọmọolórè wọn lè gba kádàrá mi
Ọmọolórè ò ní mofò
When there is no money kíní kókó
Ẹlẹ'nù pèlẹ'bẹ' olófofò
Pẹ'lú gbogbo tì ẹ sọ, kíní kókó
Kíní kókó
Credits
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.