Sutana

Aso ogo nla ni
Mi o ti ju wo rara
Aso ogo mimo ni
Mi o fi sere
Aiye n buwa pe aso yi
O ma ni yi
Won tun wipe
A nse bi egbe awon ogboni
Ko ye won
Ko le ye won
Bo se wun o
Lo n s'ola re
O pe mi s'agbo
Ki n j'alabapin
Ninu ore ofe
Mimo yi
O Bo akisa ese
Kuro Lara mi
O ra mi pada
O wo mi la so titun
Aiye e gbo

Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Sutana yi
Mimo ni o
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Ogo yi
Didan ni o
Funfun nene

Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Sutana yi
Mimo ni o
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Aso mimo ni mo wo
Funfun nene
Ogo yi
Didan ni o



Credits
Writer(s): Seun Dodo-williams
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link