Ijoba Orun

Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ o
Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ o
Mà jẹ ń kùnà, Bàbá, mú mí dé'lé o
Mà jẹ ń kùnà, Bàbá sẹ, mú mí dé'lé o

Owó tí mò ní, kò lé mù mí d'élé o
Mọto tí mo rí rà, kò lé wá mi d'élé o
Ọrẹ tí mò ní, kò lé sìn mí d'élé o
Gbogbo ìwé tí mo rí kà, wọn gbé mí re'lé o

Mà jẹ ń kùnà, Bàbá, mu mí dé'lé o
Kiń mà kú sajo bíi èéfín, mu mí dé'lé o
Aye l'ọjá, ọrùn nílé, mu mí dé'lé o
Aye l'ọjá, ọrùn nílé sẹ, mu mí dé'lé o

Mù mí dé'lé o (dé'lé)
Mù mí dé'lé o (dé'lé, dé'lé)
(Ilé) mù mí dé'lé o (dé'lé)
Mù mí dé'lé o (dé'lé o)

Mù mí dé'lé o (dé'lé)
Mù mí dé'lé o (dé'lé, dé'lé)
(Ilé) mù mí dé'lé o (dé'lé)
Mù mí dé'lé o (dé'lé o)

Mà-mà jẹ ń kùnà (ayọ, ayọ, ayọ o) Bàbá oo
(Ayọ, ayọ, ayọ o) Bàbá o
(Ayọ, ayọ, ilé ayọ) mu mí d'élé o
Mù mí dé'lé o (ayọ, ayọ, ayọ o)
Mù mí dé'lé o (ayọ, ayọ, ayọ o)
Mù mí dé'lé o (ayọ, ayọ, ilé ayọ)
Mù mí dé'lé o

Ilé ògo, ilé ayọ
Ilé ayọ, ilé àlàáfíà
Ilé ògo, ilé ayọ
Ilé ayọ, ilé àlàáfíà

Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́
Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ o
Mà jẹ kùnà



Credits
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link