Iba - Bonus Track

Ọrun ṣ'ilẹkun, I wanna have some talk with you

Nítorí rẹ mọ ṣe l'ọlá
Nítorí rẹ mọ ṣe ń ṣ'oge
Nítorí rẹ mọ ṣe ń ra moto
Mo wọle, mọ b'Olúwa mi s'ọrọ
Nítorí rẹ mọ ṣe wá l'ayé
Nítorí rẹ mọ ṣe wo aṣọ s'àrà
Nítorí rẹ mọ jí l'òwúrò
Mo wo ayé mi n'ọdẹ ye, ya

Ah-oh, aah-oh
Ah-oh, iba f'Eledua, iba f'Eledua, oh-oh
(Ah-oh) ye-ye-ye, aah-oh
Mo wọle, mọ b'Olúwa mi s'ọrọ

Nítorí rẹ mọ ṣe ń gbó ìròyìn ayọ, lai s'owó, lai sì nkan kan
Ìyà òní l'ayo ọla o, b'Olúwa ti wi bẹ náà lórí
Ooh, o wi pé kín má ṣe bẹru, so, ooh

Ah-oh, aah-oh
Ah-o, iba f'Eledua, iba f'Eledua, ah-wo-wo
(Ah-oh) ye-ye-ye, aah
Mo wọle, mọ b'Olúwa mi s'ọrọ

Nínú ìpọ́njú, nínú ìdààmú
B'ẹbi ba ń p'ona, má wọle ma b'Olúwa mi s'ọrọ
B'èmi o l'ẹyán, b'ayé bá f'ojú di mí, b'èmi on'ilẹ, ma wọle, ma b'Olúwa mi s'ọrọ

Ah-oh, aah-oh
Ah-oh, iba f'Eledua, iba f'Eledua, oh-oh, ooh
Aah, mo wọle ye, mọ b'Olúwa mi s'ọrọ

Àní, nínú ìpọ́njú, nínú ìdààmú (Ah-oh, aah-oh)
B'ẹbi ba ń p'ona, má wó ile ma b'Olúwa mi s'ọrọ (Ah-o, iba f'Eledua)
M'oní f'ojú sunkún mo, 'cause ayé l'ọjà and ọrùn n'ilé, and that's fine by me (Ah-oh, aah-oh)



Credits
Writer(s): Cobhams Emmanuel Asuquo, Bukola Elemide
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link