アウェ

Awe
Ibo lo lo ka
ta fin waoka
Ibi o ba lo jeamo

Aunty to ngbele itosi
O wa o waleyi
ati ojo meta at'abo

o wipe o
o loyun fun o
Oyun osu meji
o loyun fun o

Ani wipe o
o loyun fun o
Iwo Iwo na
o loyun fun o

Waheedi, omo Sekina, omo Muyina, omo Muhammad
Waheedi, omo Sekina, omo Muyina, omo Muhammad

Aunty, to loyun fun o
o to biolomo
Iwo Iwo na

Aunty, to loyun fun o
(Ani) o to biolomo
Iwo Iwo na

o Bimo o, o bimo
o bimo o, omo so layo

Ire lo ni mu, ese, irun ori
Iwo dudu, omo pupa
ba wo lo se ri

Waheedi, omo Sekina, omo Muyina, omo Muhammad
Waheedi, omo Sekina, omo Muyina, omo Muhammad

ah ah ah... ah ah ah
ewa wo ja l'afin Oba Ejigbo
atabo, atako
won ja l'afin oba
l'afin oba

Waheedi, omo Sekina, omo Muyina, omo Muhammad
o foju mi ri mabo
mabo nile, mabo l'oko, mabo l'eko

mama to be mama re
ni mama mi
Emi na bi temi
moo ntomo lowo
f'omo l'oyon
ma ko tire bami

abo oro lan so f'omoluabi
to ba de nu re a do n dindi
din din

Credits
Writer(s): Cobhams Emmanuel Asuquo, Bukola Elemide
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link