Ki Oluwa So Ipade Wa

Esu ma se mi
Omo elomin ni o se

Esu ma se mi
Omo elomin ni o se

Onile orita
Omo elomin ni o se

Emi o gbero ika senikeni
Emi o gbero ika senikeni
Oluwa ko so pade wa

Emi o gbero ika senikeni
Emi o gbero ika senikeni
Oluwa ko so pade wa
Atawa to n lulu ateyin to n jo
ka ma fekun ohun ose ya

Atawa to n lulu ateyin to n jo
ka ma fekun ohun ose ya

Moti layo ninu Jesu
Halleluyah
Oba mimo lofife ramipada
Titi aye lemi oma kaleluya
Halleluyah
Oba mi olore
Mokiyin pupo
ka ma fekun ohun ose ya
Tunde Ibukun ose
ka ma fekun ohun ose ya
Oyinbo oni... mi o
ka ma fekun ohun ose ya
Tunde lawrency mi
ka ma fekun ohun ose ya
Oko kudi owo
ka ma fekun ohun ose ya
Amodemaja roloye mi
ka ma fekun ohun ose ya
Mokiyin pupo
ka ma fekun ohun ose ya



Credits
Writer(s): Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link