Ore Mi E Se Pelepele
ore mi ye se pele
ore mi ye se pele
b'aye ban fé ko rora jaye
aye o feni fòoro a f'ori eni
baye ban fé ko rora jaye
aye o feni fooro
a fori eni
ore mi ye se pèlè pèlè
esigiri ni ile rami joofe
anyofe ku o ao ma ma reni kan
erin ku o moongudu fi je
efon ku o moongudu fi je
moongudu wa ku ko reni ti o je ohun
aye le oo
ore mi ye se pèlè pèlè
ore mi ye se pèlè pèlè
b'aye b'an fé
ko rora jaye o
aye o feni fooro
a f'oori eni
b'aye b'an fé
ko rora jaye o
aye o feni fooro
a f'oori eni
ore mi ye se pèlè pèlè
B'owo bade o
ebi a wa é wa
B'owo ba de o
ore a wa e wa
B'owo bade o
ebi a wa é wa
B'owo ba de o
ore a wa e wa
ore mi ye se pèlè pèlè.
ore mi ye se pele
b'aye ban fé ko rora jaye
aye o feni fòoro a f'ori eni
baye ban fé ko rora jaye
aye o feni fooro
a fori eni
ore mi ye se pèlè pèlè
esigiri ni ile rami joofe
anyofe ku o ao ma ma reni kan
erin ku o moongudu fi je
efon ku o moongudu fi je
moongudu wa ku ko reni ti o je ohun
aye le oo
ore mi ye se pèlè pèlè
ore mi ye se pèlè pèlè
b'aye b'an fé
ko rora jaye o
aye o feni fooro
a f'oori eni
b'aye b'an fé
ko rora jaye o
aye o feni fooro
a f'oori eni
ore mi ye se pèlè pèlè
B'owo bade o
ebi a wa é wa
B'owo ba de o
ore a wa e wa
B'owo bade o
ebi a wa é wa
B'owo ba de o
ore a wa e wa
ore mi ye se pèlè pèlè.
Credits
Writer(s): Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
Altri album
- Coronavirus
- Aregbesola: Agent of Change
- Sir, Gabriel Olabamiji Adeagbo 1933 - 2013
- Hrm, Oba Michael Adedotun Aremu Gbadebo
- Seeing Is Believing (Gbogbo Oju L'onri)
- 51 Lex Presents Ogunpa Flood Disater
- 51 Lex Presents Nigeria Si Ma Dun
- 51 Lex Presents Mo Lo Mo Won Lowo
- 51 Lex Presents Moti Pinu Laye Mi
- 51 Lex Presents Motun Gbede
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.