Alowo Ma Jaiye

A lowo ma jaye eyin lemo
Awon to laye lana da
won ti ku won ti lo
A lowo ma jaye eyin lemo
Awon to laye lana da
won ti ku won ti lo
To ba lowo ko fi logba sara re o
Ko jeun to da, ko woso to da
Ko gbadun Ara re, ko se faaji dogba
Bo ya lola, bo ya lola
Iku le de o
Olojo n ka jo, Olojo n ka jo
Eda gbagbe a ti sun o



Credits
Writer(s): Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link