Eni Ri Nkan He
Eni ri nkan he
To fe ku pelu e ooo
Owo eni to ti sonu nko
Aye laba aye lao fi silesi
Duro na w'eyin re wo oo
Agbajowo mani
Won lo n gberudori
Awon omo wa emamaje kan t'araka
Eni lari oooo ko ma s'eda tomola
Ni se laye yin eda kan to leyin ni
Kaparapo ka rori
Koju t'elegan l'agbara bami
E s'ami ase
U-u-u, opa kan o p'ejo o
Eje k'oju yin la ke wari pe pelebe n t'obe
A-a-a
Agbajo owo mani
Won lo gberu d'ori
Awon omo wa emama je kan taraka

Agbagba ilu mo juba o, k'iba mi se o, iba o
Agbagba ilu mo juba o, k'iba mi se o, iba o
Omode ilu mo juba o, ye o k'iba mi se o, iba o
Omode ilu mo juba o, ye o k'iba mi se o, iba o
Okunrin ilu mo juba o, ye o k'iba mi se o, iba o
Okunrin ilu mo juba o, ye o k'iba mi se o, iba o
Obirin ilu mo juba o, ye o k'iba mi se o, iba o
Obirin ilu mo juba o, ye o k'iba mi se o, iba o
Eso pele aye yi male, eso pele aye yi male
Aye o, aye o, aye o, aye
Eje ka sora f'aye
Eso pele aye yi male, eso pele aye yi soro
Aye o, aye o, aye o, aye
Eje ka sora f'aye
Eje ka f'eso jaye o (erora)
Oye ka f'eso jaye (erora)
Aye o, aye o, aye o, aye o (erora)
Eba je ka f'eso jaye (erora)
Aye o, aye o, aye o, aye o (erora)
Eba je ka f'eso jaye o (erora)
Eso pele laye mawa gba o (erora)
Eba je ka f'eso jaye (erora)
Aye o, aye o, aye o, aye o (erora)
Oye ka f'eso jaye (erora)
Aye o, aye o, aye o, aye o (erora)
Eba je ka f'eso jaye (erora)
L'ola Oluwa, ere nitiwa o, l'ola Oluwa ere ni tiwa
L'ola Oluwa, ere nitiwa o, l'ola Oluwa ere ni tiwa
B'ewure ba lo s'ode ajere bo wale o
L'ola Oluwa, ere nitiwa o, l'ola Oluwa ere ni tiwa
L'ola Oluwa, ere nitiwa o, l'ola Oluwa ere ni tiwa
B'aguntan ba lo s'ode ajere bo wale o
L'ola Oluwa, ere nitiwa o, l'ola Oluwa ere ni tiwa
L'ola Oluwa, ere nitiwa o, l'ola Oluwa ere ni tiwa
T'ani un o ro temi fun?
Ayafi baba l'oke, ayafi baba l'oke
Nitoripe?
Eleda awa ko ma se dawa da bukata wa
Alara
Eleda awa ko ma se dawa da bukata wa
Alara
Eleda awa ko gberere ko omo egbe awa
Obagiji mi o, oba mimo, jare ma mawada s'aida o
Adara yio si dara, laye wa o adara yio si dara laye wa, adara, egbe Obey e'fokan bale o
Oya ka jo jo, ere ti ya o
Oya ka jo jo, ere ti ya o
Ere ti ya o, oya k'ajoyo
Ijo ti ya o, oya k'a jo jo o
Sere funmi omoge, sere funmi o
Ere ti ya o, egbe gbajumo o nbo o
Oya ka jo jo, ere ti ya o
Oya ka jo jo, ere ti ya o
Sere funmi omoge, sere funmi o
Ere ti ya o, egbe gbajumo o, ijo ya
Igba nba jo, lonilu gbe'lu arijo sebi oba
Igba nba jo, lonilu gbe'lu arijo sebi oba
Omo arijo se bi oba o, ijo ya
Igba nba jo, lonilu gbe'lu arijo sebi oba
Omo arijo se bi oba o, ijo ya
Igba nba jo, lonilu gbe'lu arijo sebi oba
Igba nba jo, lonilu gbe'lu lo
Igba nba jo, lonilu gbe'lu arijo sebi oba
Igba nba yo, lonilu gbe'lu lo

Credits
Writer(s): Ebenezer Remilekun Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
Altri album
- Coronavirus
- Aregbesola: Agent of Change
- Sir, Gabriel Olabamiji Adeagbo 1933 - 2013
- Hrm, Oba Michael Adedotun Aremu Gbadebo
- Seeing Is Believing (Gbogbo Oju L'onri)
- 51 Lex Presents Ogunpa Flood Disater
- 51 Lex Presents Nigeria Si Ma Dun
- 51 Lex Presents Mo Lo Mo Won Lowo
- 51 Lex Presents Moti Pinu Laye Mi
- 51 Lex Presents Motun Gbede
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.