Dele Davis

Baba wa olu orun

Baba wa Ja Jehovah o
J'owo ma ma je a m'osi
Sin wa de ile ola

Baba wa olu orun
Baba wa Ja Jehovah o
J'owo ma ma je ka m'osi
Sin wa de ile ola

Baba wa olu orun

Baba wa Ja Jehovah o
J'owo ma ma je a m'osi
Sin wa de ile ola

Emi k'ole gbagbe Mose Orimolade (Orimolade)
Emi k'ole gbagbe Mose (Orimolade)
O ti kekere m'oju Oluwa (Orimolade)
O d'agbalagba sinu imole (Orimolade)

Awa k'ole sai sope (Baba wa l'oke)
(Baba wa l'oke), (Baba wa l'oke)



Credits
Writer(s): King Sunny Adé
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link