Ori Mi Ko Ni Buru (Jujju High-Life Yoruba)

Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o, yee
Ori mi, ko ni buru o
Letter t'Oluwa ba ko, ko seni to le pada
Ori mi, ko ni buru o...

Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Letter t'Oluwa ba ko, ko seni to le pada
Ori mi, ko ni buru o...

Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Ire kaluku o, lowo eleda lo wa
Oluwa ko ma gbagbe mi

Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Ire kaluku o, lowo Eleda lo wa
Oluwa ko ma gbagbe mi

Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Ire kaluku o, lowo Eleda lo wa
Oluwa, ko ma gbagbe mi



Credits
Writer(s): Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link